url
stringlengths
37
41
id
stringlengths
1
5
text
stringlengths
2
134k
title
stringlengths
1
120
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10744
10744
Pierre Abelard
Pierre Abelard
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10745
10745
Janez Drnovsek Janez Drnovsek (May 17, 1950 – February 23, 2008) A bí ní ọdún 1950. Ó jẹ́ olóòtú ìjọba Slovenia ní 1992 sí 2002. Lẹ́yìn èyí ni ó di àrẹ ilẹ̀ náà. Ní ọdún 1999 ni àìsàn kan ń bá a jà ní kíndìnrín. Ẹ̀kọ́ nípa ‘economics’ ni ó kà. Ó sì di ọmọ ilẹ́ asòfin ilẹ̀ slovenia ni ọdún 1986. Iṣẹ́ ribiribi ni ó ṣe láàrin ọdún mẹ́wàá tí ó fi ṣe olóòtú ìjọba. Ó jẹ́ kí ilẹ̀r eẹ̀ dara pọ̀ mọ́ European union àti NATO ní 2004. Oṣù kéjìlá ọdún 2007 bí ó fi ipò àrẹ ilẹ̀ slovenia sílẹ̀. Ó kú nígbà tí ó di ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógọ́ta.
Janez Drnovsek
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10746
10746
Mohammed Yunus Muhammad Yunus (Bẹ̀ngálì: , pipe ) (ojoibi 28 June 1940) je omo ilè Bangladesh. Wón bí i ní 1940 fún ebí olówó kan ní Chittagong. Gosimíìtì ni bàbá rè. Ìyá rè jé Sofia Khatun. Mama rè yìí máa n ran àwon òtòsì lówó. Ìwà yìí sì ran Mohammed. Nígbà tí òun náà dàgbà, ó dí ilé-ìfowópamó tí a ti lè máa yá àwon òtòsì lówó sílè. Won kò nílò láti ní ìdúró kankan. Irú bánkì yìí ni í wá di community Bank lóde òní Mohammed Yunus ló kókó dá a sílè. Yunus tí ní irú bánkì yìí nínú abúlé tó tó 35,000 nínú abúlé 68,000 tí ó wà ní Bangladesh. Ó ti yá òpòlopò ènìyán kówó. Obìnrin ló pò jù nínú àwon tí ó n yáwó lówó rè. Òun ni ó gba Ẹ̀bùn Nobel ti 2006
Mohammed Yunus
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10758
10758
Ede yoruba
Ede yoruba
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10763
10763
Napoleon Bonaparte <ns>0</ns> <revision> <parentid>544362</parentid> <timestamp>2021-04-27T12:11:30Z</timestamp> <contributor> <username>Agbalagba</username> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> Napoléon Bonaparte (15 August 1769 – 5 May 1821) jẹ́ olórí ológun àti adarí òṣèlú àti ọmọ bíbí ìlú Corsica ní ilẹ̀ Faranse. Ó di ìlú-mọ̀ọ́ká ní àsìkò ìyípadà ìṣèjọba ilè Faranse, tí ó sì léwájú àwọn ìjangbara oríṣiríṣi ní àsìkò ogun. Gẹ́gẹ́ bí Napoleon I, òun ni ọba ilẹ̀ Faranse láti ọdún 1804 sí ọdún 1814, àti 1815. Napoleon ṣe àkóso ìjọba ilẹ̀ Yuroopu àti àgbáyé fún bí ọdún mẹ́wá, nígbà tí ó ń léwájú nínú àwọn ogun oríṣiríṣi tí a mọ̀ sí Napoleonic Wars. Ó ja ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun, tí ó sì borí àwọn ogun tí ó sì mu láti gba àwọn ilé lọ́pọ̀lọpọ̀ fún ìjọba Faranse, tí ó sì darí ilẹ̀ Yuroopu lápapọ̀ ṣáájú kí ìjọba rẹ̀ tó ṣubú ní ọdún 1815. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn adarí ní orílẹ̀ àgbáyé tí wọ́n sì ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìṣèjọba rẹ̀ jákè-jádò àgbáyé. Ó sì wà nínú àwọn adarí tí ó gbayì jùlọ ní inú ìtàn àgbáyé.
Napoleon Bonaparte
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10770
10770
Àwọn Ogun Napoleon OGUN NAPOLEON Ìjàgbara tí a ń pe ní revolution tí ó ṣẹlẹ̀ ní France jẹ́ kí Fance ní ọ̀tá púpọ̀ ní ìlú Òyìnbó. Èyí ni ó sì fa ogun tí ó ṣẹlẹ̀ láàrin 1792 sí 1815 tí ó fẹ́rẹ̀ máa dáwó dúró. Ní àsìkò ogun yìí, ilẹ̀ Faransé ní Ọ̀gágun kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Napoleon Bonaparte. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun ni Napoleon ṣẹ́. Lẹ́yìn ìgbà tí ó ti ṣẹ́gun wọ̀nyí, ó sọ ara rẹ̀ di emperor ní 1804. Lẹ́yìn ìgbà tí ó ti di olórí ilẹ̀ Faransé tán ó tún fẹ́ di olórí gbogbo ìlú Òyìnbó. Nítorí ìdí èyí, gbogbo ìlú Òyìnbó ni ó wá gbógun tì í kí àbá rẹ̀ yìí má baà lè ṣẹ. Àwọn ìlú tó ń bá ilẹ̀ Faransé jà nígbà náà ni Austria, Prussia, Russia, Britain àti Spain. Àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Faransé pọ̀ gan-an ni. Wọ́n ṣẹ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun. Àwọ́n eléyìí tí ó ṣe pàtàkì jù ni ogun Marengo àti Hohenlinden ní 1800 ti Austerlitz ní 1805 àti ti Jena ní 1806. Ìṣẹ́gun yìí fún Napoleon ní agbara láti máa darí ilẹ̀ ìlú Òyìnbó. Ṣùgbọ́n sá, àwọn ológun ojú omi ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì lágbára gan-an ni. Ọ̀gá wọn ni Lord Nelson. Wọ́n ṣẹ́gun ọmọ ogun ilẹ̀ Faransé ní ogun Nile ní 1798. Èyí ni kò jẹ́ kí ilẹ̀ Faranse rí ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì gbà. Inú bí Napoleon, kò jẹ́ kí àwọn ọja ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì kọjá sí àwọn ilẹ̀ ìlú Òyìnbó mìíràn mọ́. Àìrí ọjà ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì yìí dá wàhálà sílẹ̀ fún àwọn ilẹ̀ yòókù. Spain yarí. Ó gbógun ti Napoleon. Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì lọ ran Spain lọ́wọ́. Ẹni tí ó ṣaájú ọmọ ogun ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì lọ ni Arthur Wellesley tí ó padà wá ń jẹ́ Duke of Wellington. Wọ́n ṣẹ́gun àwọn ìja kan. Ó ṣe, Russia dara pọ̀ mọ́ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì àti Spain. Napoleon ṣígun lọ sí Russia ṣùgbọ́n gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ ni ó kí sí ọ̀hún. Torí gbogbo ìṣẹ̀gun wọ̀nyí, Bsritain, Prussia, Sweden, Russia àti Astria para pọ̀ láti bá ilẹ̀ Faranse jà. Wọ́n ṣẹ́gun. Wọ́n wọ Paris ní 1814. Ní 1815, wọ́n lé Napoleon lọ sí Elba. Ó sá àsálà ó sì wá bá ọmọ ogun Britain àti Prussia jà ni Waterloo. Wọ́n ṣẹ́gun Napoleon wọ́n wá lé e lọ sí St Helena.
Àwọn Ogun Napoleon
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10771
10771
Konrad Adenauer Wọ́n bí Konrad Adenauer ní 1876. Ó kú ní 1967. Òun ni Chancellor West German Federal Republic ní 1949 sí 1963. Òun ni ó dá Christain Democratic Party sílẹ̀ òun sì ni alága rẹ̀ láti 1945 títí di 1966. Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n ti ṣẹ́gun Jẹ́mánì tán, ó fún Jẹ́mánì ní òfin (Constitution) tí ó fi ni lọ́kàn balẹ́ Ó sì jẹ́ kí àwọn ìlú Òyìnbó yòókù fún Jẹ́mánì láyè nínú ẹgbẹ́ àfọwọ́sowọ́pọ̀ (Western Alliance) wọn. Ó sa gbogbo agbára láti jẹ́ kí ìparí ìjà wà láàrin ilẹ̀ Fransi àti Jẹ́mánì ṣùgbọ́n kò fi àyè (accommodation) gba Rọ́síà.
Konrad Adenauer
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10772
10772
Kàlẹ́ndà Gregory Kalenda Gregory ni kalenda ti o n je lilo julo kakiri.
Kàlẹ́ndà Gregory
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10773
10773
Oṣù Osù jemó ìgbà tàbí àkókò tí a n lo ìwé-ìwo ojó fún tí àyípadà rè sì máa n pé bíi ojú ojó tí ó sì farapé bí òsùpá se n sisé. Osù àti òsùpá ní ìbásepò tó dánmórán. Kí a tólè mo bí osù se n sisé, a gbódò ní òye púpò nípa bí òsùpá se n sisé. Òdiwòn tí òsùpá àti osù fi n sisé kòju "ókàn dín lógbòn sí métà lé láàdóta ojó lo (29.53) days.
Oṣù
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10776
10776
People's Democratic Party <ns>0</ns> <revision> <parentid>571115</parentid> <timestamp>2023-06-12T18:03:58Z</timestamp> <contributor> <username>Enitanade</username> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> Peoples Democratic Party [PDP] ("Ẹgbẹ́ Dẹmokrátíkì àwọn Aráàlú") jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú yìí sílẹ̀ lọ́dún 1998. Àwọn ni ọmọ ẹgbẹ́ wọn ṣe ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà títí di ọdún 2015 kí ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress tó gbàjọba àpapọ̀ lọ́wọ́ wọn. Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́, Umaru Musa Yar'Adua àti Goodluck Jonathan ni ẹgbẹ́ yìí jẹ kí ẹgbẹ́ APC tó dà wọ́n lágbo nù lọ́dún 2015, tí Ààrẹ Muhammadu Buhari tí ẹgbẹ́ APC fi wọlé gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.
People's Democratic Party
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10779
10779
PDP <ns>0</ns> <revision> <parentid>532124</parentid> <timestamp>2020-04-25T21:43:34Z</timestamp> <contributor> <username>EmausBot</username> </contributor> <minor /> <comment>Bot: Fixing double redirect to People's Democratic Party</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format>
PDP
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10828
10828
Alfred Adler Alfred Adler jẹ́ oníṣègùn òyìnbó ọmọ orílẹ̀-èdè Austria. Wọ́n bí Adler ní ọdún 1870. Ó kú ní ọdún 1973 is. Ó jẹ́ oníṣègùn àrùn ọpọlọ tàbí wèrè (psychiatrist). Òun ni ó dá ilé-ẹ̀kọ́ tí ó n jé ‘School of Individual psychology’ sílẹ̀. Ọ̀gbẹ́ni Freud ni ó kókó n tè lé sùgbón ó yapa kúrò ní òdò rè lọ́dún 1911. Ó tako ìtẹmpẹlẹ mọ́ ọ̀rọ̀ ìbá ra-ẹnì lòpò (sex). Lójú rẹ̀, wàhálà tí ènìyàn ni láti sa agbára láti yọ ara eni kúrò ní ipò eni àá fojú ténbélú (inferiority Complex).
Alfred Adler
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10829
10829
Robert Adam Robert Adam Wọ́n bí Adam ní 1728. Ó kú ní 1792. Yaléyalé (architect) ni. Ọmọ ilẹ̀ Scotland ni. Ọkùnrin mẹ́rin ni àwọn òbí rẹ̀ bí. Ó jẹ́ ọkan nínú wọn. Díẹ̀ lára àwọn ilé tí ó yà ni Harewood House, York; Osterley Park, Kedleston Hall, Derbyslire; Luton Hoo, Bedfordshire àti Kenwood.
Robert Adam
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10830
10830
John Adams John Adams je oloselu omo ile Amerika. Wọ́n bí Adams ní 1735. Ó kú ní 1826. Òun ni ó jẹ President ilẹ̀ Àméríkà lẹ́yìn Washington. Òun ni ó kọ́kọ́ lọ ṣe ambassador ilẹ̀ oní-republic tuntun yìí ní ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì.
John Adams
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10831
10831
John Couch Adams John Couch Adams Wọ́n bí Adams ní 1819. Ó kú ní 1892. Ọmọ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ni. Onímọ̀ ìṣirò (Mathematics) ni. Astronomer sì ni pẹ̀lú. Òun àti Leverrier, astronomer ọmọ ilẹ̀ Faransé kan ni wọ́n jọ gba ogo ṣíṣe àwárí Neptune ní 1846. Òtọ̀ọ̀tọ̀ ni wọ́n ṣe iṣẹ́ tí wọ́n gba ògo rẹ̀ yìí.
John Couch Adams
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10832
10832
Samuel Adams Wọ́n bí Adams ní ọdún 1722. Ó kú ní 1803. Olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Àmẹ́ríkà ni tí ó ń fẹ́ kí àyípadà wa. Boston ni wọ́n ti bí i. Láti nǹkan bíi 1765 ni ó ti ń sọ pé ẹni tí kò bá ní aṣojú kò gbọdọ̀ san owó-orí (no taxation without representation). Ó gbé ‘Boston tea-party’ ga. Ní 1776, ó fi ọwọ́ sí ìwé òmìnira (declaration of independent).
Samuel Adams
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10833
10833
William Adams William Adams Wọ́n bí Adams ní 1564. Ó kú ní 1620. Iṣẹ́ ọkọ̀ ojú omi (navigation) ni ó ń ṣe. Dillingham, Kent ni wọ́n ti bí i ní ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì. Òun ni ọmọ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì àkọ́kọ́ tí yóò lọ sí Japan. Shogun Ieyasu ní ìfẹ́ sí i gidi ni, nítorí ìdí èyí, wọn fi ibi tí àwọn Gẹ̀ẹ́sì àti Dutch ti lè máa ṣòwò lélẹ̀ ní Japan. Eléyìí sì wà títí di 1616.
William Adams
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10834
10834
Jane Addams Jane Laura Addams A bí Addams ní 1860. Ó kú ní 1935. Ọmọ ilẹ̀ Àméríkà ni. Onímọ̀ nípa ẹ̀kọ́ tí wọ́n ń pè ní Sociology ni. Òun ni ó dá Hull House, Chicago sílẹ̀ ní 1889.
Jane Addams
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10835
10835
Joseph Addison Joseph Addison je olukowe omo Ile Geesi Wón bí Addison ní 1672. Ó kú ní 1719. Ònkòwé ni Addison olósèlú sì ni pèlú. Ó kópa nínú ‘Taller’ òun àti Steele ni wón sì jo dá ‘Spectator’ sílè.
Joseph Addison
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10836
10836
Adelard ará Bath Adelard ara Bath tabi Adelard de Bada (Latin: Adelardus Bathensis) (c. 1080 – c. 1152) je omowe ara Ilegeesi ni orundun 12th scholar. O gbajumo fun ise akoko re ati fun iyipadaede awon iwe sayensi pataki ni iworawo, itorawo, imoye ati mathimatiki latede Griki ati Larubawa si ede Latin lati atejade Larubawa, latibe ni won ti mu won wa si Apaiwoorun Europe. O keko ni Tours, o soluko fun gba die ni Laon, layin re lo rinajo lo si Apaguusu Italia, Syracuse ni Sicily, ati Antioch ni Asia Kekere. O budo si Bath ni Ilegeesi ni odun 1122. O je eni igba kanna pelu William ara Conches, o si je eni to mo sode eye to si mo fere fan.
Adelard ará Bath
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10837
10837
Olú Agúnlóyè Olu Agunloye ‘Geophysicist’ ni Dr Olú Agúnlóyè ‘ administrator’ sì ni. Wón bí Dr Agúnlóyè ní ojó kerìndínlógún osù késàn-án odún 1948. Wón bí i ní Erusu-Àkókó ní ìpínlè Ondó. Ó kàwé ní University of Ibadan láàrin 1971 sí 1974, Unversity of Reading, U.K ní 1974 àti Massachusetts Institute of Technology. Òun ni Corps Marshall àti Chief Executive, Federal Road Safety Commission télè. Òun sì ni Minister of State for Defence fún àwon Navy télé.
Olú Agúnlóyè
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10839
10839
Ìyípo
Ìyípo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10865
10865
Naijiria
Naijiria
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10866
10866
Egbe Oselu Olominira ti Puerto Rico
Egbe Oselu Olominira ti Puerto Rico
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10867
10867
Ibadan
Ibadan
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10869
10869
Abuja
Abuja
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10870
10870
Obafemi Awolowo
Obafemi Awolowo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10875
10875
Alumíníọ̀mù Chemical element with atomic number 13 Alumíníọ̀mù ( ) tabi aluminomu (; e wo "spelling" labe) je apilese kemika kan ninu adipo boron to je funfun bi fadaka to se mo. O ni ami-idamo Al ati nomba atomu 13. Ko le yo ninu omi fun ra ara re. Aluminiomu je onide to po repetejulo ninu igbele Aye, ati iketa to po repetejulo nibe leyin oksijini ati silikoni. Ohun ni o je bi 8% bi iwuwo oju ile Aye. Aluminiomu ndarapomora mo awon kemika yioku kiakia gidigidi nitorie ko le da wa fun ra re gege bi onide. Bibeeko, a le ri ni didapo mo orisirisi awon alumoni bi 270. Orisun aluminiomu ni adalu irin bauxite.
Alumíníọ̀mù
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10880
10880
Irin Irin je àdàlú ni pataki julo idẹ pelu akoonu adú larin 0.2 and 1.7 or 2.04% ni iwuwosi. Adu ni o dinwoju lati se adalu mo idẹ sugbon a tun le lo adalu awon apilese miran manganisi, kromiomu, banadiomu ati wolframu. Adu ati awon apilese miran n sise bi imule sinsin lati dena ifo ninu atomu ayonu.
Irin
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10881
10881
TLD
TLD
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10882
10882
.la <ns>0</ns> <revision> <parentid>387859</parentid> <timestamp>2013-03-08T13:34:34Z</timestamp> <contributor> <username>Addbot</username> </contributor> <minor /> <comment> Migrating 68 interwiki links, now provided by on </comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> .la je amioro orile-ede Internet ti top-level domain (ccTLD) fun orile-ede Laos.
.la
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10884
10884
.lb .lb je ti orile-ede Lebanon.
.lb
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10885
10885
.ke
.ke
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10886
10886
.kg .kg je ti ile Kyrgyzstan.
.kg
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10887
10887
.kh .kh ni amioro orile-ede ti top-level domain lori Internet(ccTLD) fun Cambodia.
.kh
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10888
10888
.ki .ki
.ki
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10889
10889
.km
.km
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10890
10890
.kn .kn je ti ile Saint Kitts ati Nevis
.kn
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10891
10891
.kp
.kp
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10892
10892
.kr .kr je ti orile-ede Guusu Korea.
.kr
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10893
10893
.kw .kw
.kw
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10894
10894
.nf .nf ile Erékùsù Nọ́rúfọ́lkì
.nf
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10895
10895
.ne .ne
.ne
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10896
10896
.nc .nc
.nc
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10897
10897
.na .na
.na
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10898
10898
.mz .mz je ti ile Mozambique
.mz
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10899
10899
.my .my je ti Malaysia.
.my
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10900
10900
.mx .mx je ti meksiko
.mx
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10901
10901
.mw .mw je ti orile-ede Malawi.
.mw
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10902
10902
.mv .mv je amioro orile-ede ti Internet fun top-level domain (ccTLD) fun orile-ede Maldives.
.mv
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10903
10903
.mu
.mu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10904
10904
.lc .lc ni amioro orile-ede lori Internet ti top-level domain (ccTLD) fun Saint Lucia.
.lc
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10905
10905
.li .li jẹ́ ti ilẹ̀ Líktẹ́ństáìnì
.li
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10906
10906
.lk .lk je ti ile Sri Lanka
.lk
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10907
10907
.lr .lr je ti ile Liberia
.lr
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10908
10908
.ls
.ls
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10909
10909
.lt .lt
.lt
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10910
10910
.mt .mt
.mt
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10911
10911
.ms .ms
.ms
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10912
10912
.mr .mr
.mr
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10913
10913
.mq
.mq
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10914
10914
.mp .mp is the Internet country code top-level domain (ccTLD) for Northern Mariana Islands.
.mp
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10915
10915
.mo
.mo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10916
10916
.lu .lu je amioro orile-ede top-level domain (ccTLD) fun Internet ti Luxembourg.
.lu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10917
10917
.lv .lv ni amioro orile-ede top-level domain (ccTLD) lori Internet fun Latvia.
.lv
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10918
10918
.ly .ly je ti orile-ede Libya.
.ly
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10919
10919
.ma
.ma
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10920
10920
.mc .mc ni amioro orile-ede top-level domain (ccTLD) ori Internet fun Monaco.
.mc
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10921
10921
.md .md je ti ile Moldofa
.md
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10922
10922
.me .me je amioro internet fun ile Montenegro.
.me
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10923
10923
.mg
.mg
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10924
10924
.mh .mh ni amioro orile-ede ti Internet fun top-level domain (ccTLD) fun Marshall Islands.
.mh
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10925
10925
.mk .mk
.mk
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10926
10926
.ml .ml ni amioro orile-ede lori Intrnet fun Mali
.ml
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10927
10927
.mm .mm ni àmì ọ̀rọ̀ orílẹ̀-èdè ti ìpele tí ó ga jùlọ lórí ẹ̀rọ ayélujára (ccTLD) fún Burma (lónìí gẹ́gẹ́bí ìṣọ̀kan ilẹ̀ Myanmar). Ó jẹ́ fífifún ní ọdún 1997. Síwájú 1989, àmì ọ̀rọ̀ ISO 3166-1 fún Burma ní BU, ṣùgbọ́n .bu ccTLD kọ̀ jẹ́ lílò rí rárá.
.mm
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10928
10928
.mn .mn je ti ile Mongolia.
.mn
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10929
10929
Julius Nyerere Julius Kambarage Nyerere (13 April, 1922 - 14 October, 1999) fi igba kan je Aare ile Tanzania ati ti Tangayika tele.
Julius Nyerere
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10930
10930
Bòtswánà <ns>0</ns> <revision> <parentid>575751</parentid> <timestamp>2023-10-04T02:00:23Z</timestamp> <contributor> <username>InternetArchiveBot</username> </contributor> <comment>Rescuing 1 sources and tagging 0 as dead.) #IABot (v2.0.9.5</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> Bòtswánà, lóníbiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bòtswánà (Tswana: ), jẹ́ orílẹ̀-èdè àdèmọ́àrinlẹ̀ tó bùdó sí Apágúsù Áfríkà. Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè únpe ara wọn bíi "Batswana" (ẹyọìkan: Motswana), sugbon awon elede miran unpe won bi "ara Botswana". Teletele o je ibi-abo Britani to unje Beshuanalandi, Botswana gba oruko tuntun leyin ominira ni ojo 30 Osu Kesan 1966. Latigba na lo lo ti unse idiboyan oselu to gbomitoro. Botswana je petele, be sini 70% je bibomole pelu Aginju Kalahari. O ni bode mo orile-ede Guusu Afrika ni gusu ati gusuilaorun, Namibia ni iwoorun ati ariwa, ati Zimbabwe ni ariwailaorun. Bode re mo Zambia ni ariwa nitosi Kazungula, Zambia ko fi be nitumo sugbon ko gun ju bi ogorun mita lo. Botswana ko ni ju eniyan to to egbeegberun meji lo nitorie o je ikan ninu awon orile-ede alabugbe kekere julo ni agbaye. Nigba ti Botswana gba ilominira latowowo Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan ni 1966, o je ikan ninu awon orile-ede to talaka julo ni Afrika pelu GDP ti enikookan bi US$70. Latigbana Botswana ti yira re pada lati di ikan ninu awon ti okowo re undagba julo lagbaye de eyi to ni GDP (agbara iraja) ti enikookan to to bi $14,000. Bakana asa oselu asoju gbale daada nibe. Ìtàn. <ns>10</ns> <id>16733</id> <revision> <id>534273</id> <parentid>122075</parentid> <timestamp>2020-05-17T15:21:13Z</timestamp> <contributor> <username>Demmy</username> <id>193</id> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> Ni orundun 19k, ogun sele larin awon Tswana ti won ti ungbe Botswana ati awon eya Ndebele ti won sese unko bo si agbegbe yi lati ariwa-ilaorun. Bakanna rogbodiyan sele pelu awon ateludo Boer lati Transvaal ni ilaorun. Leyin itoro awon olori Batswana bi Khama III, Bathoen ati Sebele fun iranlowo, Ijoba Britani fi "Bechuanaland" si abe abo re ni ojo 31 Osu Keta 1885. Ibi-ile apaariwa nigbana wa labe imojuto taara bi Ibiabo Beshuanalandi ibe lasi mo loni bi Botswana, nigba ti ibi-ile apaguusu di apa Ileamusin Cape loni o je apa igberiko ariwaiwoorun orile-ede Guusu Afrika. Opo awon eniyan to unso ede Setswana loni ungbe ni orile-ede Guusu Afrika. Nigbati Isokan ile Guusu Afrika je didasile bi orile-ede ni 1910 latinu awon ileamusin gbangba Britani ni agbegbe na, Ibiabo Bechuanaland, Basutoland (loni bi Lesotho) ati Swaziland (eyun "High Commission Territories") ko je ara re, sugbon eto wa nigbana lati safikun won lojowaju. Ipinnu ni pe ijiroro yio sele pelu awon alabugbe ibe botileje pe awon ijoba Guusu Afrika mura lati da awon ibi-ile na pada fun won, Britani dina eyi; nitorie ko sele. Idiboyan ijoba Asetolorile-ede ni odun 1948, to pile eto apartheid, ati ikesejade Guusu Afrika kuro ni Egbe Kajola ni 1961, fi opin si ero pe awon ibi-ile yi yio bo si owo orile-ede Guusu Afrika. Ifidimule ijoba britani ati idasile ijoba ibile fa idasile ni 1920 igbimo agbero meji lati soju awon ara Afrika ati ara Europe. awon ikede ni 1934 selana ijoba ati agbara ibile. Igbimo agbero ara Afrika ati ara Europe kan je didasile ni 1951, be sini isepo 1961 selana igbimo asofin adamora. Ni Osu Kefa 1964, Britani fowo si aba idasile ijoba-araeni olselu ni Botswana. Ibujoko ijoba kuro ni Mafikeng ni Guusu Afrika ni 1965, si ilu tuntun ni Gaborone, " Cara Mendapatkan Kuota Gratis 3 10 GB terbaru 2017 " ti kkojinna si bode re. Isepo 1965 fa idiboyan gbogbogbo wa ati ilominira ni ojo 30 Osu Kesan 1966. Seretse Khama, olori ninu awon egbe irinkankan fun ilominira ati ajoye Ngwato je didiboya bi aare akoko, o si tun ti je atundiboyan lemeji latigbana. Ipo aare bo sowo igbakeji aare, Quett Masire, to jje didiboyan fun ra re ni 1984 ati lemeji si ni 1989 ati 1994. Masire feyinti ni 1998. Igbakeji re Festus Mogae, je didiboyan fun ra re ni 1999 ati lekan si ni 2004. Ni 2008 ipo aare bo sowo Ian Khama (omokunrin aare akoko), to fi ipo re sile bi olori Ile-ise Iseabo Botswana lati le ba bo si ipo oloselu yi. Ijiyan lori bode pelu Namibia lori Caprivi Strip je lilaja latowo Ile-Ejo Akariaye fun Idajo ni Osu Kejila 1999, pe Erekusu Kasikili je ti Botswana. Ìṣèlú àti ìjọba. <ns>10</ns> <id>16733</id> <revision> <id>534273</id> <parentid>122075</parentid> <timestamp>2020-05-17T15:21:13Z</timestamp> <contributor> <username>Demmy</username> <id>193</id> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> boilerplate seealso">Ẹ tún wo: Foreign relations of Botswana Iselu ni Botswana unwaye labe eto orile-ede olominira oloselu asoju, nibi ti Ààrẹ ilẹ̀ Bòtswánà ti je olori orile-ede ati olori ijoba, ati labe sistemu egbe oloselu pupo. Agba apase wa lowo ijobat. Agbara Asofin wa lowo ijoba ati Iléaṣòfin ilẹ̀ Bòtswánà. Idiboyan aipe, ikewa iru re, waye ni ojo 16 Osu Kewa 2009. Lati igba ilominira, oselu ni Botswana ti je gigaba latowo Egbe Oloselu Botswana. Adajo ni ilominira latodo apase ati asofin. Gege bi Isekedere Akariaye se so, Botswana ni orile-ede Afrika to ni iwa ibaje to din julo, be sini ipo re sunmo Portugal ati Korea Guusu. Nevertheless the country is considered to have the most secretive public institutions. Orin-iyin orile-ede ni Fatshe leno la rona. Àwọn ìpín àmójútó. <ns>10</ns> <id>16733</id> <revision> <id>534273</id> <parentid>122075</parentid> <timestamp>2020-05-17T15:21:13Z</timestamp> <contributor> <username>Demmy</username> <id>193</id> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> Botswana je pinpin si sàkání 15 – sakani oko 9 ati sakani ilu 6.
Bòtswánà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10944
10944
Ìhà ìwọ̀-oòrùn
Ìhà ìwọ̀-oòrùn
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10952
10952
1 E10 m² To help compare orders of magnitude of different geographical regions  we list here areas between 10,000 km² and 100,000 km². "See also" areas of other orders of magnitude. Definition: "1 E+10 m²" = formula_1 m²
1 E10 m²
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10956
10956
Perú Peru je orile-ede ni apa guusu Amerika. Lima ni oluilu.
Perú
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10966
10966
Àkójọ àwọn orílẹ̀-èdè bí àwọn ènìyàn wọn se pọ̀sí List. Figures indicated by "UN estimate" are based on the July 1, 2009 estimate by the United Nations Department of Economic and Social Affairs – Population Division.
Àkójọ àwọn orílẹ̀-èdè bí àwọn ènìyàn wọn se pọ̀sí
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10981
10981
Port Harcourt Port Harcourt tabi Ebute Harcourt ("Ugwe Ocha" ni èdè Igbo, "Oborokiri" ni ede Ijo) je ilu ni Naijiria ati oluilu ipinle Rivers.
Port Harcourt
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10982
10982
Kàdúná Kàdúná je ilu ni Naijiria ati oluilu Ìpínlẹ̀ Kàdúná
Kàdúná
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10986
10986
Gb Gb Gb je alfabeti yoruba pataki A, B, "C", D, E, Ẹ, F, G, Gb, H, I, J, K, L, M, N, O, Ọ, P, "Q", R, S, Ṣ, T, U, "V", W, "X", Y, "Z"
Gb
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10987
10987
Gúúsù Amẹ́ríkà Gúúsù Amẹ́ríkà
Gúúsù Amẹ́ríkà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10989
10989
Guusu Amerika
Guusu Amerika
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10993
10993
Rakunmi
Rakunmi
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10994
10994
Hàítì Haiti je orile-ede ni apa Ariwa Amerika ni erekusu Karibeani ti a mo si Hispaniola.
Hàítì
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=11001
11001
Gámbíà Gambia tabi Orile-ede Olominira ile Gambia je orile-ede ni apa Iwoorun Afrika.
Gámbíà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=11002
11002
Liberia Làìbéríà tabi Orile-ede Olominira ile Làìbéríà je orile-ede ni Iwoorun Afrika. O fi ègbé kan Ilè Sàró tí a mò si Sierra Leone ní ìwǫ oòrùn, orílę èdè Guinea ni gúúsù ati orílę èdè Côte d'Ivoire ní ìlà oòrùn. Etí Òkun Làìbéríà kún fún ijù igi mangrove nìbitì ilę nínú loun pęlú èrò kékeré ję kìkì ijù tí ó na apá sí ìtélè ewéko gbígbe. Ilu naa ni o ni 40% ninu eyi ti o seku ni igi Iju Guinea ti Apa Guusu. Afefe ilu Làìbéríà je ti gbigbona ila idameji aye, pelu òjo pupo ni osu May titi di osu October ni asiko òjò ati afefe oye lile fun iyoku odun.
Liberia
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=11003
11003
Senegal Sẹ̀nẹ̀gàl () tabi Orile-ede Olominira ile Senegal je orile-ede ni Iwoorun Afrika. Senegal ni Okun Atlantiki ni iwoorun, Mauritania ni ariwa, Mali ni ilaorun, ati Guinea ati Guinea-Bissau ni guusu. Sinu die lo ku ko yipo Gambia ka patapata si ariwa, ilaorun ati guusu, ibi to se ku nikan ni eti okun Atlanti Gambia Ifesi ile Senegal fe to 197,000 km², be si ni o ni onibugbe bi 13.7 legbegberun. Dakar ni oluilu re to wa lori Cap-Vert Peninsula ni eti Okun Atlantiki. Bi iye ida kan ninu meta awon ara Senegal ni won n gbe labe ila aini kakiriaye to je US$ 1.25 lojumo.
Senegal
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=11004
11004
Ilaoorun Afrika
Ilaoorun Afrika
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=11005
11005
Iwoorun Afrika
Iwoorun Afrika
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=11006
11006
Àríwá Áfríkà
Àríwá Áfríkà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=11008
11008
Kristina Fermandez de Kirchner
Kristina Fermandez de Kirchner
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=11009
11009
Kristina Fernandez de Kirchner
Kristina Fernandez de Kirchner
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=11012
11012
Godwin Babátúnde Kofi Akran Godwin Babatunde Kofi Akran (a bí Ọba Akran ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1936) lọ sí Salvation Army School, Kakawa, Lagos láàrin 1946 sí 1947, Methodist School, Badagry àti Methodist Teachers Training College, Ìfàkì-Èkìtì láàrin 1956 sí 1957. Ó lọ sí International Press Institute, University of East Africa, Nairobi, Kenya ní 1977. Ó di reporter fún West African Plot ní 1961, News Editor, New Nigerian Newspapers 1975-1977. Ó di Ọba ìlú Badagry gẹ́gẹ́ bíi De Whenọ Ahọlu Mẹnu Toyi 1 ní ọdún 1977.
Godwin Babátúnde Kofi Akran
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=11013
11013
Tunji Braithwaite Tunji Braithwaite je oloselu omo ile Naijiria. Lọ́ọ́yà ni Dr T́únjí Braithwaite olóṣèlú sì ni Wọ́n bí Dr Braithwaite ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1943. Òun ni ó dá Nigeria Advanced Party (NAP) tí wọ́n ti parẹ́ sílẹ̀. Ó gbé àpótí fún ipò Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà lábẹ́ ẹgbẹ́ Grassroots Democratic Advanced Movement (DAM).
Tunji Braithwaite
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=11014
11014
Káyọ̀dé Ẹ̀ṣọ́ Bobakayode Eso (18 September, 1925 - 16 November, 2012)A bí Justice Kayọde Èsó ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1925. Ó lọ sí Holy Trinity School Iléṣà láàrin 1933-1939 àti Trinity College, Durban láàrin 1949-1953. Wọ́n pè é sí Bar ní Lincoln Inn, London ní 1954. Òun ni Chief Judge àkọ́kọ́ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní Western Court of Appeal ipimle naa. Wọ́n yàn án ní Justice Supreme Court, Lagos ní 1978. Ó ti fẹ̀yìn tì báyìí.
Káyọ̀dé Ẹ̀ṣọ́