url
stringlengths
37
41
id
stringlengths
1
5
text
stringlengths
2
134k
title
stringlengths
1
120
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10578
10578
.cs .cs je fun opo odun amioro orile-ede top-level domain (ccTLD) fun Czechoslovakia. Sugbon, orile-ede na tuka si Czech Republic ati Slovakia ni 1993, awon orile-ede mejeji yi si gba ccTLDs ti won otooto: .cz ati .sk nitelerawon. Ilo .cs wa dopin die die, o si je pipare patapata ni January 1995.
.cs
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10579
10579
.zr .zr
.zr
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10580
10580
Top-level domain Top-level domain
Top-level domain
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10582
10582
Sango
Sango
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10584
10584
Sikiru Ayinde Barrister Sikiru Ayinde Barrister ) je olorin fuji omo ile Naijiria. Ayinde Barrister bere si korin ta ni odun 1966- 2008, Barrister gbe awo orin to po to 127 jade. Ninu won ni "Oke Agba" (1980), "Ijo Olomo" (1983), "Nigeria" (1983), "Military" (1984), "Barry Wonder" (1987), "Fuji Garbage" (1988), "Music Extravaganza" (1990) ati "Fuji Waves" (1991). Ìgbésí Ayé r̀ẹ. A bí Síkírù Àyìndé Barrister nínú ẹb́i Sàláwù Balógun ní ìlú Ìb̀adàn, bàbá rẹ̀ Salawu Balógun jẹ́ Alápatà Ẹran, nígbà tí ìyá rẹ̀ jẹ́ Oníṣòwò pẹ́pẹ̀ẹ̀pẹ́. Ó lọ Ilé-Ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Muslim Mission àti Ilé-Ìwé Model ti Mushin tó wà nílù Èkó. Lẹ́yìn èyí ni ó lọ sí ilé-ìwé àkọ́ṣẹ́-mọṣẹ́ ti Yaba Polytechnic láti kọ́ nípa ìmọ̀ òǹtẹ̀wé àti àwọn iṣẹ́ ọwọ́ mìíràn. Àyìndé Barrister bẹ̀rẹ̀ iṣé orin kíkọ láti ìgbà kékeré rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí 'Ají-Sààrì' tàbí "Ají-wérẹ" lásìkò Àwẹ̀ àwọn Musulumi; bí ó ṣe ń ṣiṣẹ́ rẹ̀ náà ló ń kọrin pẹ̀lú rẹ̀ . Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Atẹ̀wé fún Ilé-Iṣẹ́ tí ó pọn ọtí Nigerian Breweries, lẹ́yìn náà ni wọ́n gbà gẹ́gẹ́ bí òǹtẹ̀wé ránṣẹ́ ní Ilé-Iṣẹ́ Ológun Ilè Nàìjíríà Nigerian Armylát̀arí akitiyan rẹ̀́, lásìkò ogun abẹ́lé.</ref> Ó ṣíṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Ọmọ ogun ní Ẹ̀ka kẹwàá '10th Brigade' ti ìpín Kejì '2nd Division' ti Ilé-Iṣẹ́ Ológun Nàìjíríà lábẹ́ Ọ̀gágun 'Adéníran' ó sì jà fitafita ní Awka, Abagana àti Onitsha. Ikú àti ìsìnkú rẹ̀. Barrister ku ni ojo 16 osu kejila 2010 ni London nibi to ti lo gba iwosan fun arun ito-suga(diabetes). Isinku re waye ni ogbo ojo osu kejila odun 2010 ni ile re ti o wa ni Eko.
Sikiru Ayinde Barrister
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10585
10585
Èkó <ns>10</ns> <id>10589</id> <revision> <id>502220</id> <parentid>20836</parentid> <timestamp>2015-08-09T21:51:16Z</timestamp> <contributor> <username>YiFeiBot</username> <id>11398</id> </contributor> <minor /> <comment>Bot: Migrating 1 langlinks, now provided by on </comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> Èkó (tàbí Lagos ní èdè Gẹ̀ẹ́sì , US also ; ) ni ìlú tó ní èrò tó pọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ní gbogbo ilẹ̀ Áfríkà. Èkó jẹ́ ilé-ajé pàtàkì ní gbogbo Áfríkà àti oríta òkòwò ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Èkó gẹ́gẹ́bí ìlú-nínlá ni o ní GDP kẹrin tó pọ̀jùlọ ní Áfríkà, ibẹ̀ sì ni èbúté ọkọ̀-ojúomi tó tó bijùlọ àti tó láápọn jùlọ ní ilẹ̀ Áfríkà. Èkó ni ìkan láàrin àwọn ìlú tí ó ń ní ìgbèdàgbà kíákíá jùlọ ní àgbáyé. Èkó ní orúkọ tí àwọn Yorùbá ń pè ìlú erékùsù tí ó ti di olú ìlú àti ibùjoko ìjoba gbogbo-gbòò fún ilè Nàìjíríà ní ojó òní. Ìlú Yorùbá ní, ṣugbọ́n orúkọ ti àwọn ènìyàn àgbáíyé fí ń pè é ni èyí ti àwọn Òyìnbó Potogi tí o kọ́ bẹ etíkun ilẹ̀ Yorùbá wò fún un. Orúkọ náà ni “Lagos”, eyi ti ìtumọ rẹ̀ jásí “adágún” tàbí “ọ̀sà”, nítorí pé ọ̀sà ni ó yí ìlú náà ka... Àwọn Ẹ̀yà Yorùbá ti Àwórì ni ó kọ́kọ́ tẹ̀dó si agbègbè Ìlú Èkó, lábé ìsàkóso àti Ìtọnà olórí wọn, Ọ̀lọ̀fin, àwọn Àwórì kọ́kọ́ tẹ̀dó sí erékùsù Ìddó, Léyìn ìgbà náà ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ si ní wọnú àwọn agbègbè yókù Èkó láti tẹ̀dó. Ní séntúrì karùndínlógún {15th Century}, Ìlú Èkó, bọ́ sí abẹ́ ìsàkóso Ìjọba Benin. Ìgbà náà ni àwọn Ológun Ìlú náà sọ agbègbè ìlú náà ní "Èkó", eléyìí, tí ó túmò sí [Ibi tí àwọn Ológun tí ń simi} Ní èdè Edo/Benin. Gbogbo eléyìí ṣẹlẹ̀ lábẹ́ olórí àwọn Benin ní ìgbà náà Ọba Ọ̀rọ̀gbà. Léyìn tí èyí ṣẹlẹ̀, ni Ìjọba Benin fi Baálẹ̀ jẹ́ oyè, láti máà M'ójútó/Se Àkóso, àti Gbígbà Ìsákọ́lè {Tribute} ìlú náà bíi agbègbè lábé-fé Ìjọba ńlá ti Benin. Ọba Yorùbá àkọ́kọ́ ti Ìlú Èkó jẹ́, ní Ọba Aṣípa. Ní ọdun-ún 1472, àwọn Òyìnbó Pọ́tókì{Portuguese} dé si ilè Èkó, àwọn Pọ́tókì náà ní Òyìnbó àkókó, tí o máà de Ilè -Èkó láti Erékùsù Orílè-ẹ̀dẹ̀ Europe ní ìgbà náà.
Èkó
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10592
10592
Lagos
Lagos
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10593
10593
Àwọn Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Nàìjíríà Awon Agbègbè Ijoba Ibile Naijiria 744 ni o wa ni Naijiria
Àwọn Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Nàìjíríà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10599
10599
Baháí <ns>0</ns> <revision> <parentid>514305</parentid> <timestamp>2022-07-06T13:04:04Z</timestamp> <contributor> <username>Sowoletoyin</username> </contributor> <comment>Mo se àfikún àwòrán #WPWPYO</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> Bahai Ẹ̀sìn kan tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1863 tí ó ń mú gbogbo èyí tí ó dára lára èsìn mìíran lò tí ó sì ń mú kí gbogbo àwọn ènìyàn ayé para pọ̀. Àwọn tí ó ń sin ẹ̀sìn yìí ni wọ́n ń pè ní Bahais.
Baháí
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10603
10603
Aberdeen Ìlú ńlá kan nìyí ní ìlà-oòrùn àríwá ilẹ̀ Scotland. Ara Káúntì (County) Aberdeenshire ni ó wà tẹ́lẹ̀. Láti oṣù kárùn-ún ọdún 1975 ni ó ti di ara Grampian. Wọ́n máa ń pe Aberdeen ní ‘granite city’. Ó ní Yunifásítì kan tí wọ́n dá sílẹ̀ ní 1494. Aberdeen Angus ni wọn máa ń pe orúkọ àgùntàn kan tí ó gbajúmọ̀ ní Aberdeen. Àwọn ará ìlú Aberdeen ni wọ́n ń pè ní Aberdonian.
Aberdeen
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10604
10604
Aberdeenshire Agbègbè kan ní ìlà-oòrùn Scotland ni Aberdeenshire. Ó ní àwọ òkè ní apá ìwọ̀-oòrùn rẹ̀. Ibi tí ó ga jù níbẹ̀ ni a ń pè ní Cairngorm. Àwọn òkè yìí jẹ ojú ní gbèsè. Orí òkè wọ̀nyí ni odò Don àti Dee ti sun wá. Ní apá ìlà-oòrùn Aberdenshire, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni ó jẹ wọ́n lógún. Bí wọ́n ti ń dáko ni wọ́n ń sin nǹkan ọ̀sìn. Bèbè òkun ibẹ̀ ní òkúta. Buchan Ness tí ó wà ní Aberdeenshire ni ìlú tí ó kángun jù ní ìlà-oòrùn ilẹ̀ Scotland. Àwọn ìlú tí ó ṣe pàtàkì ní Aberdeenshire ni Aberdeen, Peterhead, fraserburgh, Inverturie, Ballatre àti Huntly. Iṣẹ́ àgbẹ̀ ni ó wọ́pọ̀ jù ní Aberdeenshire. Wọ́n dá ilé-iṣẹ́ ẹja sílẹ̀ ní Aberdeen, fraserburgh àti Peterhead. Àwọn ènìyàn ti ó wà ní agbègbè yìí ní 1961 jẹ́ 298, 503.
Aberdeenshire
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10605
10605
Abergavenny Abergavenny je ilu oja ní ilè Welsi. Ìlú náà wà ní ibi tí odo Ilok àti Gavenny ti pàdé. Máìlì márùn-ún ni ìlú yìí sí Monmouth, ní apá ìwọ̀-oòrùn. Àwọn ènìyàn tó ń gbé ìlú yìí ní 1961 jẹ́ 9,625.
Abergavenny
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10606
10606
Sani Abacha Sani Abacha (20 September 1943 – 8 June 1998) je Ogagun Ile-Ise Ologun ile Naijiria ati Olori orile-ede Naijiria lati ojo 17 osu Kokanla odun 1993 titi de ojo 8 osu Kefa 0dun 1998 to ku lojiji. ìgbé ayé rẹ. Wọn bí Abacha ní ìlú Kano ni Nàìjíríà. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Nigeria Military Training College tí Ìlú Kaduna Ọgbà ipò igbimọ in Ọdún 1963 leyin tí ó dé láti ikẹ eko tó cadeti ni ìlú Aldershot ni England. Ìgbà Ikú rẹ. Ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹfà ni ọdún 1998,abacha ku si Aṣọ Rock tí àwọn Ààrẹ ni ìlú Abuja.Wọn sìn Abacha ní ìlà náà tí Mùsùlùmí. Àwọn kàn ní májẹ lè ní opáa, àwọn kan ni àwọn apá yàn ni wọ́n paa, àti bẹẹbẹẹ ló ní pàtó kosi ẹni tí ó mọ ìdí ikú rẹ.Lẹ́yìn ikú rẹ, wọn fi Ọgbẹ́ni Abdulsalami Abubakar ṣe olú dárí tí ìpínlẹ́ ni Oṣù Kẹ̀wá ọdún 1998.
Sani Abacha
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10613
10613
Abdulsalami Abubakar <ns>0</ns> <revision> <parentid>459309</parentid> <timestamp>2017-09-17T10:03:12Z</timestamp> <contributor> <username>Demmy</username> </contributor> <comment>/* Itokasi */</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> Abdulsalami Abubakar (ojoibi June 13, 1942) je omo ologun ara ile Naijiria ati Olori ijoba ile Naijiria lati ojo 9 osu 6, 1998 titi di ojo 29, osu 5, 1999 leyin igba ti Sani Abacha ku.
Abdulsalami Abubakar
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10615
10615
Àkójọ àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ Nàìjíríà <ns>0</ns> <revision> <parentid>576880</parentid> <timestamp>2024-01-24T03:15:43Z</timestamp> <contributor> <username>InternetArchiveBot</username> </contributor> <comment>Rescuing 1 sources and tagging 0 as dead.) #IABot (v2.0.9.5</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> Àtòjọ àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ Nàìjíríà lọ́wọ́lọ́wọ́. Egbe oselu ti ikokan awon gomina na je: NB: Party affiliation changes regularly as a result of the state of defections in Nigeria's political party system.
Àkójọ àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ Nàìjíríà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10618
10618
.cc .cc je ti Àwọn Erékùsù Kókósì (Cocos Islands)
.cc
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10619
10619
.cd .cd
.cd
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10620
10620
.cf .cf je àmìọ̀rọ̀ orílẹ̀-èdè top-level domain fun Internet (ccTLD) ti ile Central African Republic. It is administered by the Central African Society of Telecommunications.
.cf
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10621
10621
.cg .cg
.cg
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10622
10622
.ch .ch je ti ile Swítsàlandì
.ch
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10623
10623
.ci .ci is the Internet country code top-level domain (ccTLD) for Côte d'Ivoire.
.ci
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10624
10624
.ck .ck je ti ile Erekusu Kuuk
.ck
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10625
10625
.cl .cl ni amioro orile-ede top-level domain lori Internet (ccTLD) fun Tsile.
.cl
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10626
10626
.cn .cn je ti ile china
.cn
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10627
10627
.co .co
.co
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10628
10628
.cr .cr
.cr
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10629
10629
.cu .cu je ti ile Kuba
.cu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10630
10630
.cv .cv
.cv
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10631
10631
.cx .cx
.cx
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10632
10632
.cy .cy
.cy
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10633
10633
.cz .cz
.cz
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10634
10634
.dj .dj
.dj
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10635
10635
.dk .dk
.dk
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10636
10636
.dm .dm je ti ile Dòmíníkà
.dm
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10637
10637
.do .do
.do
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10638
10638
.dz .dz ni amioro orile-ede (ccTLD) fun Algeria.
.dz
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10639
10639
.ec .ec je ti ile Ẹ̀kùàdọ̀
.ec
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10640
10640
.ee .ee je ti orile-ede Estonia.
.ee
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10641
10641
.eg .eg
.eg
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10642
10642
.er
.er
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10643
10643
.es .es
.es
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10644
10644
.et
.et
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10645
10645
.eu .eu je ti orile Isokan Europe (EU).
.eu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10646
10646
.fi .fi
.fi
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10647
10647
.fj .fj
.fj
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10648
10648
.fk .fk
.fk
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10649
10649
.fm .fm ni amioro orile-ede fun top-level domain lori Internet (ccTLD) fun Federated States of Micronesia, to je adipo awon erekusu ni Okun Pasifiki.
.fm
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10650
10650
.fo .fo ni amioro orile-ede top-level domain (ccTLD) fun awon Erekusu Faroe.
.fo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10651
10651
.fr .fr je ti orile-ede Fransi
.fr
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10652
10652
.ga .ga
.ga
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10653
10653
.gd .gd
.gd
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10654
10654
.ge .ge
.ge
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10655
10655
.gf .gf
.gf
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10656
10656
.gg .gg
.gg
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10657
10657
.gh .gh je amioro orile-ede fun top-level domain ti Internet (ccTLD) fun ile Ghana.
.gh
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10658
10658
.gi .gi
.gi
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10659
10659
.ky .ky ni amioro orile-ede lori Internet fun top-level domain (ccTLD) fun Cayman Islands.
.ky
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10660
10660
.kz .kz je ti orile-ede Kasakstan.
.kz
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10661
10661
.gl .gl je ti ile Greenland.
.gl
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10662
10662
.gm .gm
.gm
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10663
10663
.gn .gn je ti ile Guinea
.gn
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10664
10664
.gp <ns>0</ns> <revision> <parentid>368396</parentid> <timestamp>2013-03-08T13:12:27Z</timestamp> <contributor> <username>Addbot</username> </contributor> <minor /> <comment> Migrating 67 interwiki links, now provided by on </comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> .gp
.gp
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10666
10666
.gq .gp
.gq
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10667
10667
.gs .gs
.gs
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10668
10668
.gt .gt ni amioro orile-ede ti Internet fun top-level domain (ccTLD) orile-ede Guatemala.
.gt
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10669
10669
.gu .gu ni amioro orile-ede lori Internet ti top-level domain (ccTLD) fun orile-ede Guam.
.gu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10670
10670
.gw .gw "Global Web" ni amioro orile-ede top-level domain lori Internet (ccTLD) fun Guinea-Bissau.
.gw
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10671
10671
.gy .gy je ti ile Guyana
.gy
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10672
10672
.hk .hk
.hk
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10673
10673
.hm .hm
.hm
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10674
10674
.hn .hn
.hn
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10675
10675
.hr .hr ni ami orile-ede Internet ti top-level domain (ccTLD) fun orile-ede Croatia (Kroatíà: ).
.hr
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10676
10676
.ht .ht
.ht
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10677
10677
.hu .hu je ti orile-ede Hungary.
.hu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10678
10678
.id .id
.id
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10679
10679
.ie .ie
.ie
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10680
10680
.il .il
.il
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10681
10681
.im .im ni amioro orile-ede lori Internet ti top-level domain (ccTLD) fun Isle of Man.
.im
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10682
10682
.in .in
.in
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10683
10683
.io .io ni amioro Internet top-level domain (ccTLD) fun Ileagbegbe Okun India Britani.
.io
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10684
10684
.iq .iq je amioro orile-ede ti top-level domain lori Internet (ccTLD) fun Iraq.
.iq
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10685
10685
.ir .ir je ti ile Ìránì
.ir
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10686
10686
.is .is
.is
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10687
10687
.it .it je ti Italia.
.it
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10688
10688
.je
.je
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10689
10689
.jm .jm
.jm
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10690
10690
.jo
.jo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10691
10691
.jp .jp je amioro orile-ede fun top-level domain ti Internet (ccTLD) fun orile-ede Japan.
.jp
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10697
10697
Japan Japan (日本, Nihon or Nippon) jẹ́ orílẹ̀-èdè erékùṣù ní Ìlà Oòrùn Asia. Ó pàlà pẹ̀lú Òkun Pàsífíìkì, o wa ni ilaorun Okun Japan, Saina, Ariwa Korea, Guusu Korea ati Rosia, o gun lati Okun Okhotsk ni ariwa de Okun Ilaorun Saina ati Taiwan ni guusu. Awon leta ti won fi n ko oruko Japan tumo si "orisun orun", eyi lo je idie ti a fi n pe Japan ni "". Japan jẹ́ arkipelago àwọn Erékùṣù 6,852. àwọn erékùṣù ibẹ̀ tí ó tóbi jùlọ ní Honshū, Hokkaidō, Kyūshū àti Shikoku, ti àpapọ̀ wọ́n jẹ́ èdè mẹ́tàdínlọ́gọ́rùún (97%) ìtóbi ilẹ̀ Japan. Opo awon erekusu wonyi je oloke, opo je onileru; fun apere, ibi gigajulo ni Japan, Oke Fuji, je onileru. Japan je orile-ede ikewa to iye awon eniyajulo, pelu awon eniyan ti won to egbegberun 128. Agbegbe Titobiju Tokyo, to ni oluilu "de facto" Tokyo ati awon ibile ayika re, ni o je agbegbe metropoli titobijulo lagbaye pelu iye eniyan to to egbegberun 30. Iwadi iseoroayeijoun fihan pe awon eniyan ti ungbe ni Japan lati igba to ya bi igba Okutaijoun Oke. Igba akoko ti a ko gbo nipa oruko Japan ninu iwe akoole je ninu awon iwe itan Saina lati orundun 1k SK. Ipa latodo awon orile-ede miran je titele pelu idagbe igba pipe bo se han gbangba ninu itan Japan. Ni igbeyin orundun 19k ati 20k ijabori ninu Ogun Saina ati Japan Akoko, Ogun Rosia Japan, ati Ogun Agbaye 1k gba Japan laye lati fe ile re nigba itoja ogun. Ogun Saina ati Japan Keji odun 1937 tan titi de Ogun Agbaye 2k, to wa sopin ni 1945 leyin ijubombu atomu si Hiroshima ati Nagasaki. Lati igba atunse ibagbepo re ni 1947, Japan ti di oba onibagbepo olokan pelu obaluaye atiileasofin aladiboyan tounje Diet mu. Alagbara itokowo ninla, Japan ni o ni itokowo keta totobijulo lagbaye gegebi GIO oloruko ati gegebi ifiwe agbara iraja. Bakanna o tun je atajalode kerin titobijulo ati arajalatode kerin titobijulo lagbaye. Botilejepe Japan lonibise ti jowo eto re lati gbe ogun, o di ile-ise ologun odeoni mu fun abo ati ise alafia. Leyin Singapore, Japan lo ni ipaniyan to kerejulo lagbaye. Gegebi UN ati WHO se diye, Japan lo ni ireti igbeaye gigunjulo larin gbogbo awon orile-ede lagbaye. Bakanna o tun ni iku omo-owo tokerejulo keta, gegebi UN se so.
Japan
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10699
10699
Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ará ilẹ̀ Ṣáínà je orile-ede ni orile Ásíà.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10701
10701
Àkójọ àwọn olúìlú ìpínlẹ̀ Nàìjíríà Àwọn wọ̀nyí ni àkójọ àwọn olúìlú àwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríà.
Àkójọ àwọn olúìlú ìpínlẹ̀ Nàìjíríà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10703
10703
Ikeja Ikeja je oluilu ipinle Eko ni guusu iwo oorun Naijiria . Awon olugbe rẹ, ni asiko ikaniyan odun 2006 je 313,196. Papa ọkọ ofurufu ti Murtala Muhammed wa ni ilu naa. Ikeja ilu ti Femi Kuti ti wa, ti o si je ilu iya Lagbaja. Ile ise radio bii Eko FM ati Radio Lagos wa ni ilu Ikeja. Itan ilu yi. Ikeja, eyi ti won n pe ni “Akeja” tele, je ilu ti won fi oruko re lela latari orisa awon Awori ti ilu ota.
Ikeja
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10704
10704
Adó-Èkìtì Adó Èkìtì jẹ́ ìlú ńlá kan ní apá Ìwọ̀ Oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríàtí ó sì jẹ́ olú-Ìlú fún Ìpínlẹ̀ Èkìtì. Ètò ọrọ̀ aje wọn. Lára àwọn obun tí wọ́n fi ń ṣọrọ̀ aje ní ìlú Adó-Èkìtì ni kí á gbohùn sáfẹ́fẹ́, lára àwọn ilé-iṣẹ́ ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́ tí ó jẹ́ amóhù-máwòrán ti ìjọba àpapọ̀ Nigerian Television Authority (NTA) ti ó wà ní ìlú Adó-Èkìtì. Bákan náà ni wọ́n tún ní ilé-iṣẹ́ amóhù-máwòrán ti Ìpínlẹ̀ tí wọ́n pe ní "Ekiti State Television (BSES)". Àwọn ilé-iṣẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ti asọ̀rọ̀-mágbèsì náà kò gbẹ́yìn, lára wọn ni: Oríṣiríṣi ohun ọrọ̀ aje ni ó wà ní ìlú Adó, tí àwọn ènìyàn sì ṣòwò kárà-kátà ohun ọ̀gbìn oríṣiríṣi bíi: ẹ̀gẹ́, iṣu, àwọn nkan oníhóró lóríṣirí, tábà òwú tí wọ́n sì ma ń ṣe iṣẹ́ aṣọ híhun àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ètò ìṣèjọba ìbílẹ̀. Lọ́wọ́ lọ́wọ́, ẹni tí ó jẹ́ adarí ìbílẹ̀ pàtàkì akọ́kọ́ ní ìlú Adó ni Ọba tàbí Èwí Adó ni Rufus Aladesanmi III tí wọ́n jẹ́ "Èwí ti Adó", tí wọ́n tẹ́rí gbadé lẹ́yì Èwí àná, Ọba "Samuel Adeyemi George-Adelabu I" ní ọdún 1990.
Adó-Èkìtì
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10705
10705
Ado Ekiti
Ado Ekiti
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10706
10706
Ìlú Benin Ilu Benin tabi Benin City je ilu ni Naijiria ati oluilu ipinle Edo.
Ìlú Benin
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10707
10707
Ilu Benin
Ilu Benin
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10708
10708
Ralph Ellison Ralph Waldo Ellison (March 1, 1914 – April 16, 1994) je oluko ati olukowe ara Amẹ́ríkà.
Ralph Ellison
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10730
10730
Alex Ekwueme Alex Ifeanyichukwu Ekwueme (ojoibi October 21, 1932) je oloselu ati Igbakeji Aare ile Naijiria si Aare Shehu Shagari ni Igba Oselu Keji lati 1979 de 1983.
Alex Ekwueme
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10731
10731
African National Congress
African National Congress
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=10737
10737
Ènìyàn Yorùbá
Ènìyàn Yorùbá