url
stringlengths
37
41
id
stringlengths
1
5
text
stringlengths
2
134k
title
stringlengths
1
120
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17171
17171
Onueke Onueke je ìlú ní Nàìjíríà.
Onueke
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17172
17172
Òpobò Opobo je ìlú ní Nàìjíríà.
Òpobò
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17173
17173
Orerokpe Orerokpe je ìlú ní Nàìjíríà.
Orerokpe
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17174
17174
Orhuwhorun Orhuwhorun je ìlú ní Nàìjíríà.
Orhuwhorun
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17175
17175
Oron, Nàìjíríà Oron, Nàìjíríà je ìlú ní Nàìjíríà.
Oron, Nàìjíríà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17176
17176
Orlu Orlu je ìlú ní Nàìjíríà.
Orlu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17177
17177
Osubi Osubi je ìlú ní Nàìjíríà.
Osubi
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17178
17178
Otu Jeremi Otu Jeremi je ìlú ní Nàìjíríà.
Otu Jeremi
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17179
17179
Ovwian Ovwian je ìlú ní Nàìjíríà.
Ovwian
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17180
17180
Ozoro Ozoro je ìlú ní Nàìjíríà.
Ozoro
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17181
17181
Potiskum Potiskum je ìlú ní Nàìjíríà.
Potiskum
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17182
17182
Sango Otta Sango Otta jé ìlú olórúkọ ní ìpinlẹ̀ Ògùn Nàìjíríà.
Sango Otta
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17183
17183
Ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí, Nàìjíríà Ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí, Nàìjíríà jẹ ìlú to tobi jù ni Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúsù Ṣakí ti Oke-Ogun ìpínlè Ọ̀yọ́ , Nàìjíríà.. Àwọn ọmọ Yorùbá ti Ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí tan mọ àwọn ifọn ti dahomey ati àwọn Ifọn ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun . Olóyè wọn Ọba ìlú náà wá lati ìdílé Obàtálá, Ọbàlùfọ̀n ti Ọ̀yọ́ Ile. Ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí duro láàrin Igboho, Ago-amodu ati Oje Owode (ti won pe ni "Aha" tele) Saki, Ago-Are ati Iseyin. Apejuwe. Orúkọ ti Ọba Ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí njẹ ni Ọbalùfọ̀n ti Ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí. Awọn ìdílé to nṣe jọba ni Daodus, Baloguns ati Ogboros. O wà ni àárin Ṣakí ati Ìgbòho ni agbègbè Oke-Ogun, Òyó Arewa Senatorial District ti ilu Oyo ni Yorùbá. Oke-Ogun ni Ìjọba kẹkẹ mewa, àyàfi Ògbómọ̀ṣọ́. Oke-Ogun bẹẹ láàrin Òyó ati ìpínlè Kwara lọwọlọwọ. Agbègbè Ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí bèèrè lati Ìséyìn osi lópin ni Bakase, ilu kékeré kan pelu ààlà ti Ìpínlè Òyó ati Ìpínlè Kwara. Awon Ara Ilu. Ilu jẹ ibarapọpọ ti o ni akọkọ, awọn eniyan ti o jẹ ti ẹya Yoruba ti wọn sọ ede Yoruba, botilẹjẹpe awọn ẹgbẹ to kere lati ibomiiran ni Nigeria ati Afirika ni aṣoju. Bii gbogbo awọn ọmọ Yoruba miiran, wọn jẹ ọmọ lati Oduduwa. Eto idile ti o gbooro se pataki si asa ati igbagbo ile Yoruba. Iṣowo[edit source]. Wiwa ti nkan àlùmọnì wà ni agbègbè, bíi tantalite, columbite, cassiterite, kaolin, ati granite. Ìjọba Ìpínlè Òyó ti n ṣètò lapidary kan lati toju awon nnkan àlùmọnì ati ọjà òkúta Iyebiye ni káríayé ni ìlú Ìbàdàn níbití àwọn iwakusa le ṣe ta ọja wọn. Iṣẹ àgbẹ̀ ni iṣẹ àwọn ọmọ ìlú Ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí. Yàtò si àwọn ipa àkọkọ́ ti pipesè oúnjẹ ati ibi ààbò, oojọ, awọn ohun èlò aiṣe ile-iṣẹ, o tun jẹ orísun pàtàkì ti owo-wiwọle ni Ìjọba agbègbè.
Ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí, Nàìjíríà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17184
17184
Sepeteri,Nigeria
Sepeteri,Nigeria
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17185
17185
Suleja Suleja je ìlú ní Ipinle Niger, Nàìjíríà.
Suleja
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17186
17186
Surulere, Lagos State Surulere, Lagos State je ìlú ní Nàìjíríà.
Surulere, Lagos State
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17187
17187
Udu, Nàìjíríà Udu, Nàìjíríà je ìlú ní Nàìjíríà.
Udu, Nàìjíríà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17188
17188
Ughelli Ughelli je ìlú ní Nàìjíríà.
Ughelli
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17189
17189
Ukat Aran Ukat Aran je ìlú ní Nàìjíríà.
Ukat Aran
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17190
17190
Wukari Wukari je ìlú ní Nàìjíríà.
Wukari
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17191
17191
Yaba Yaba je ìlú ní Nàìjíríà.
Yaba
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17192
17192
Frederick Lugard British colonial administrator (1858–1945) Frederick John Dealtry Lugard, 1st Baron Lugard (22 January 1858 – 11 April 1945), tí wọ́n mọ̀ sí Sir Frederick Lugard láàárín 1901 àti 1928, jẹ́ jagunjagun British , alágbàṣe , olùwákiri Áfíríkà àti alámòójútó ìjọba amúnisìn. Ó jẹ́ Gómìnà Hong Kong tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ rí (1907–1912), gómìnà ìkẹyìn Southern Nigeria Protectorate (1912–1914), kọmíṣọ́nà gíga àkọ́kọ́ (1900–1906) àti Gómìnà ìkẹyìn (1912–1914) Northern Nigeria Protectorate]] àti Adarí gómìnà Nàìjíríà (1914–1919) àkọ́kọ́. Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́. Wọ́n bí Lugard ní Madras (Chennai nísìnyí) ní India, ṣùgbọ́n wọ́n tọ́ ọ ní Worcester, England. Ó jẹ́ ọmọkùnrin Reverend Frederick Grueber Lugard, àlùfáà àwọn ológun Bírítéènì ní Madras, àti ìyàwó rẹ̀ kẹtà Mary Howard (1819–1865), ọmọbìnrin Reverend John Garton Howard tí ó kéré jùlọ (1786–1862), ọmọkùnrin kékeré ọmọọnílẹ̀ láti Thorne àti Melbourne nítòsí York. Arákùnrin bàbá rẹ̀ ni Sir Edward Lugard, Adjutant-General in India láti 1857 sí 1858 àti Permanent Under-Secretary of State for War ní ilé-iṣẹ́ ogun láti 1861 di 1871. Lugard kẹ́kọ̀ọ́ ní Rossall School àti Royal Military College, Sandhurst. Orúkọ 'Dealtry' jẹ́ ìmọrírì Thomas Dealtry, ọ̀rẹ́ bàbá rẹ̀.
Frederick Lugard
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17194
17194
Gombe State
Gombe State
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17197
17197
Ipinle Gombe
Ipinle Gombe
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17201
17201
Joseph Orji Joseph Orji je Gomina Ipinle Gombe lati October 7, 1996 titi de August 1998.
Joseph Orji
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17202
17202
Mohammed Bawa Mohammed Bawa (6 April 1954 – 26 May 2017) je Gomina Ipinle Gombe lati August 1998 titi de May 1999.
Mohammed Bawa
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17203
17203
Abubakar Habu Hashidu Abubakar Habu Hashidu je Gomina Ipinle Gombe lati May 29, 1999 titi de May 29, 2003.
Abubakar Habu Hashidu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17206
17206
Jobele Jobele je ilu kekere ni Ipinle Oyo ni Naijiria. Ilu yi ni ibujoke agbegbe ijoba ibile Afijio.
Jobele
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17209
17209
Àwọn ọmọ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin látin Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ The Nigerian National Assembly delegation from Oyo comprises three Senators representing Oyo South, Oyo Central, Oyo North and fourteen Representatives representing the following federal constituencies: Ona-Ara/Egbeda, Iseyin/Kajola/Iwujola/Itesiwaju, Ibadan North- East/South- East, Lagelu/Akinyele, Ibarapa East/Ido, Ibadan North, Oluyole, Atigbo/Saki East/Saki West, Ibadan North West/South West, Ibarapa Central/Ibarapa North, Afijio/Atiba/Oyo East/Oyo West, Ogo-oluwa/Surulere Oluyole, Ogbomosho-North/South/Orire, and Olurunssogo/Orelope/Irepo.
Àwọn ọmọ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin látin Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17210
17210
Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Ile-igbimo Asofin Ipinle Oyo ni apa ijoba Ipinle Oyo to n se ofin ni ipinle na gege bi ilana-igbagbepo Naijiria 1999 se so.
Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17211
17211
Oyo State House of Assembly
Oyo State House of Assembly
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17214
17214
Taofeek Oladejo Arapaja Taofeek Oladejo Arapaja je oloselu omo ile Naijiria ati Igbakeji si Gomina Ipinle Oyo, Adebayo Alao-Akala lati 2007. Teletele, o je asoju ni Ile-igbimo Asofin Naijiria fun Ibadan South-West/Ibadan North-West Constituency lati 2003 de 2007 ati Alaga, Agbegbe Ijoba Ibile Guusu-Iwoorun Ibadan ni 1999 de 2003.
Taofeek Oladejo Arapaja
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17219
17219
Ìwé ìkọjá Nàìjíríà
Ìwé ìkọjá Nàìjíríà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17220
17220
Plateau State
Plateau State
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17223
17223
Sokoto State <ns>0</ns> <revision> <parentid>69258</parentid> <timestamp>2024-02-01T01:04:29Z</timestamp> <contributor> <username>EmausBot</username> </contributor> <minor /> <comment>Fixing double redirect to Ìpínlẹ̀ Sokoto</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format>
Sokoto State
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17225
17225
JTY Aguyi-Ironsi
JTY Aguyi-Ironsi
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17226
17226
Agbegbe Apaariwa Naijiria
Agbegbe Apaariwa Naijiria
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17227
17227
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Idemili Agbegbe Ijoba Ibile Guusu Idemili je ijoba ibile ni Ipinle Anambra ni Naijiria. Ibujoko re wa ni Ojoto.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Idemili
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17228
17228
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ido-Osi Agbègbè Ìjoba Ìbílè Ìdó-Òsi jé ìjoba ìbílè ní Ìpínlè Èkìtì tó wà ní Nàìjíríà. Ibùjókò ó rè wà ní ìlú u Ìdó-Òsi. Ìtókasí. Ìdó-Òsi wà ní Ìpínlè Èkìtì, l'órílè èdè Nàìjíríà. Ìjoba ìbílè ná à kún fún àwon ìlú àti ìletò àtètèdáyé tí ó kúndùn-un èkó kíkó, tí wón sì ní ìdáméwà á àkójopò o àwon òmòwé gíga yíká órílè èdè ná à, tó sì tún jé òkan nínú u agbègbè ìjoba Ìpínlè Èkìtì. Ó sún mó àwon agbègbè ìjoba mìíràn bí i Mòbà, Ìjerò, Ìlejeméje àti Adó. Ìjoba Ìbílè yì í ní àwon ìlú wònyì í l'ábé e rè: Àayè, Ìdó, Ùsì, Ayétòrò, Ìlógbò, Òsi, Ìfàkì, Òrìn, Odò-Orà, Òkè-Orà, Ìlógbò, Igbólé, àti àwon ìletò kéréje-kéréje bí i: Ìpólé, Òbajì, Odò Obà-Aládélúsì Òkálàwá, Òkè Esè, Tèmigbolá, Òrìn, Àayè, Ìfisìn, Òrà. Olú ilé işé Ìjoba Ìbílè yì í ni wón fi s'odo si Ìdó Èkìtì, tí ilé ìşàkóso sì wà ní àárín-in ìlú Ìdó àti Ùsì. Láàrín-in àwon akegbé e rè ní Ìpínlè Èkìtì, Ìdó-Òsi ní awon onímò ìwe dunjú l'átàrí i àtètèdá a ìlé ìjosìn àti ilé èkó alákòóbèrè s'ílù ú Ùsì Èkìtì ní kété tí ilé èkó o ti Adó Èkìtì, tí ń şe Olú-Ìlù Ìpínlè ná à, gbin'lè. Lára àwon ènìyàn pàtàkì àti òtòkùnlú ìlú láti Ìjoba Ìbílè ná à lati rí gómìnà Ìpínlè ná à télè rí, [Olúşégun Òní], enití ó wá láti ìlú Ìfàkì.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ido-Osi
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17229
17229
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifako/Ijaye Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifako/Ijaye wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifako/Ijaye
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17230
17230
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifedayo Agbegbe Ijoba Ibile Ifedayo je ijoba ibile ni Ipinle Osun ni Naijiria. Ibujoko re wa ni Oke-Ila.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifedayo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17231
17231
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifedore Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifedore wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifedore
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17232
17232
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifelodun, Ìpínlẹ̀ Kwárà Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifelodun, Ìpínlẹ̀ Kwárà wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifelodun, Ìpínlẹ̀ Kwárà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17233
17233
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifelodun, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun Agbegbe Ijoba Ibile Ifelodun je ijoba ibile ni Ipinle Osun ni Naijiria. Ibujoko re wa ni Ìkìrun.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifelodun, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17234
17234
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifo Agbegbe Ijoba Ibile Ifo je ijoba ibile ni Ipinle Ogun to wa ni Naijiria.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17235
17235
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Igabi Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Igabi wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Igabi
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17236
17236
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Igalamela-Odolu Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Igalamela-Odolu wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Igalamela-Odolu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17237
17237
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Igbo-Etiti Agbegbe Ijoba Ibile Igbo-Etiti je ijoba ibile ni Ipinle Enugu towa ni Nigeria. Ibujoko re wa ni ilu Ogbede.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Igbo-Etiti
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17238
17238
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Igbo-Eze Agbegbe Ijoba Ibile Ariwa Igbo-Eze je ijoba ibile ni Ipinle Enugu towa ni Nigeria. Ibujoko re wa ni ilu Enugu-Ezike.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Igbo-Eze
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17239
17239
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Igbo-Eze Agbegbe Ijoba Ibile Guusu Igbo-Eze je ijoba ibile ni Ipinle Enugu towa ni Nigeria. Ibujoko re wa ni ilu Ibagwa-Aka.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Igbo-Eze
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17240
17240
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Iguegben Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Iguegben wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Iguegben
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17241
17241
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ihiala Agbegbe Ijoba Ibile Ihiala je ijoba ibile ni Ipinle Anambra ni Naijiria. Ibujoko re wa ni Ihiala. Awon ilu miran ni agbegbe ijoba ibile yi ni Okija ati Uli.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ihiala
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17242
17242
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ihitte Uboma Agbegbe Ijoba Ibile Ihitte/Uboma je ijoba ibile ni Ipinle Imo ni Naijiria. Ibujoko re wa ni Isi Nweke
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ihitte Uboma
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17243
17243
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ilaje Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìlàjẹ jẹ́ ìjọba-ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Òǹdó tó wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ gúnwà sí ìlú Igbokoda. Àwọn Ìlájẹ jẹ́ ẹ̀yà tí ó dá yàtọ̀ tí wọ́n ṣẹ̀ sí etídò àwọn ẹ̀yà elédè Yorùbá tí wọ́n tàn yíká etí odò ìpínlẹ̀ Òndó, Ògún, Èkó, àti Delta.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ilaje
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17244
17244
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìlàòrùn Ijebu Agbegbe Ijoba Ibile Ilaorun Ijebu je ijoba ibile ni Ipinle Ogun to wa ni Naijiria.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìlàòrùn Ijebu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17245
17245
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Ijebu Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Ijebu wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Ijebu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17246
17246
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá-Ìlàòrùn Ijebu Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá-Ìlàòrùn Ijebu wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá-Ìlàòrùn Ijebu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17247
17247
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ijebu-Ode Agbegbe Ijoba Ibile Ijebu-Ode je ijoba ibile ni Ipinle Ogun to wa ni Naijiria.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ijebu-Ode
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17248
17248
Agbegbe Ijoba Ibile Ijebu-ode
Agbegbe Ijoba Ibile Ijebu-ode
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17249
17249
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ijero Agbegbe Ijoba Ibile Ijero je ijoba ibile ni Ipinle Ekiti towa ni Nigeria. Ibujoko re wa ni ilu Ijero-Ekiti.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ijero
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17250
17250
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ijumu Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ijumu wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ijumu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17251
17251
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ika-Annang Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ika-Annang wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ika-Annang
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17252
17252
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá-Ìlàòrùn Ika Agbegbe Ijoba Ibile Ariwa-Ilaorun Ika je ijoba ibile ni Ipinle Delta ni Naijiria.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá-Ìlàòrùn Ika
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17253
17253
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikara Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikara wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikara
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17254
17254
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Ika Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Ika wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Ika
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17255
17255
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikeduru Agbegbe Ijoba Ibile Ikeduru je ijoba ibile ni Ipinle Imo ni Naijiria. Ibujoko re wa ni Iho
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikeduru
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17256
17256
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikeja Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikeja wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikeja
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17257
17257
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìkẹ́nnẹ́ Agbegbe Ijoba Ibile Ikenne je ijoba ibile ni Ipinle Ogun to wa ni Naijiria.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìkẹ́nnẹ́
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17258
17258
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikere Agbegbe Ijoba Ibile Ikere je ijoba ibile ni Ipinle Ekiti towa ni Nigeria. Ibujoko re wa ni ilu Ikere-Ekiti.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikere
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17259
17259
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikole Agbegbe Ijoba Ibile Ikole je ijoba ibile ni Ipinle Ekiti towa ni Nigeria. Ibujoko re wa ni ilu Ikole-Ekiti.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikole
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17260
17260
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikom Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikom wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikom
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17261
17261
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikono Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikono wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikono
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17262
17262
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìkòròdú Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìkòròdú wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìkòròdú
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17263
17263
Umaru Farouk Abdul Mutallab Umaru Farouk Abdul Mutallab je omo orile-ede Naijiria to je fifesunkan pe o tiraka lati yin bombu abefanka ninu ifoloke 253 baalu ti Northwest Airlines ni Ojo Keresimesi December 25, 2009.
Umaru Farouk Abdul Mutallab
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17268
17268
Abdulfarouk Umar Muttalab
Abdulfarouk Umar Muttalab
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17269
17269
Umar Farouk Abdul Mutallab
Umar Farouk Abdul Mutallab
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17271
17271
Saint Petersburg
Saint Petersburg
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17273
17273
Bozhe, Tsarya khrani!
Bozhe, Tsarya khrani!
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17274
17274
Petrograd
Petrograd
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17276
17276
Èdè Fínlándì Finnish ( , or "suomen kieli")
Èdè Fínlándì
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17277
17277
Pétérù 1k ilẹ̀ Rọ́síà Peter I the Great or Pyotr Alexeyevich Romanov (Rọ́síà: )
Pétérù 1k ilẹ̀ Rọ́síà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17278
17278
Finnish language
Finnish language
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17280
17280
Rómù Olómìnira Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn ará Rómù (Latini: Res publica Romanorum) ni a n pe igba itan Romu ti awon ara Romu le oba ikeyin won kuro lori ite lati sepilese oselu. Igba oselu tabi igba olominira bere pelu iwolulo oba tokeyin ara Etruski, eyun Tarkuinu Onigberaga (Tarquinius Superbus) ni 509 kJ o si dopin pelu ibori Oktabiani lori Marku Antoni ni Ija Aktiomu ni 31 kJ.
Rómù Olómìnira
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17281
17281
Roman Republic
Roman Republic
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17284
17284
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikot-Abasi Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikot-Abasi wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikot-Abasi
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17285
17285
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikot Ekpene Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikot Ekpene wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikot Ekpene
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17286
17286
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikpoba-Okha Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikpoba-Okha wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikpoba-Okha
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17287
17287
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikwerre Agbegbe Ijoba Ibile Ikwerre je ijoba ibile ni Ipinle Rivers ni Naijiria. Ibujoko re wa ni Isiokpo
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikwerre
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17288
17288
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikwo Agbegbe Ijoba Ibile Ikwo je ijoba ibile ni Ipinle Ebonyi ni Nigeria.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikwo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17289
17289
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikwuano Agbegbe Ijoba Ibile Ikwuano wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ikwuano
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17290
17290
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ila Agbegbe Ijoba Ibile Ila je ijoba ibile ni Ipinle Osun ni Naijiria. Ibujoko re wa ni Ila Orangun.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ila
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17291
17291
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ilejemeje Agbegbe Ijoba Ibile Ilejemeje je ijoba ibile ni Ipinle Ekiti towa ni Nigeria. Ibujoko re wa ni ilu Iye-Ekiti.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ilejemeje
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17292
17292
Ile Oluji Ile Oluji wà ní Nàìjíríà.. Ìpínlẹ̀. Ilẹ̀ Olúji jẹ́ ìlú kan ní ìpínlẹ̀ Ondo orílẹ̀-èdè Nigeria. Ìlú yìí jẹ́ olú- ìlú fún ìpínlẹ̀ Ile-Oluji/Okeigbo. Àwọn ìlú náà jẹ́ ọmọ Yorùbá tí babańlá wọ́n jẹ́ Oduduwa. Jegun of Ile-Oluji. Orúkọ ọba wọn. HRM Oba (Dr) Oluwole Olufaderin Adetimehin, FIIN, FCIB, Jimoko II, tí ó jẹ́ olórí ilé-ìfowópamọ́ Chartered Insurance Institute of Nigeria tẹ́lẹ̀ rí ni ọba wọn tuntun tí wọ́n dé ládé ní ọjọ́ kẹwàá, oṣù kẹfà, ọdún 2016 Ètò -ọrọ̀-ajé. Ile-Oluji jẹ́ ìlú tí ó fàyè gba ètò- ọ̀gbìn. Ó jẹ́ ọkàn lára ìlú tí ó ń ṣe kòkó jù lọ ní orílè-èdè Nàìjíríà tí ó sì ń gbé e lọ sí àwọn orílè-èdè mìíràn .ẹ̀gẹ́, iṣu, àgbàdo, àti epo pupa jẹ àwọn ohun ọgbìn tí àwọn àgbè ìlú yìí tún máa ń tẹpele mọ́. Ilé-iṣẹ́ tó ṣe pàtàkì jù ní ìlú yìí ni Cocoa Products Ile-Oluji Limited. Ó ní ọkàn nínú àwọn ilé-iṣẹ́ tó máa ń ṣe kòkó jù lọ ní ìwọ̀-oòrun Áfíríkà. Àwọn òhun tí ilé iṣẹ́ yìí ń ṣe ni "Cocoa Powder", "Cocoa Cake", "Cocoa Butter" àti "Cocoa Liquor" èyí tí wọ́n tà fún àwọn oníbàárà wọn. Lára àwọn oníbàárà wọ́n ni Promasidor Nigeria, Nestle, Fan Milk, Indcresa Productos Del Cacao ní Spain àti Theobroma B.V ní Netherlands. Oluji Pure Cocoa Powder jẹ́ ọ̀kan lára ohun tí ilé-iṣẹ́ yìí ṣe. Ètò-ẹ̀kọ́.. Ilé-ìwé gíga ìjọba àpapọ̀ Pólì Federal Polytechnic, "Ile-Oluji" ni ilé-ìwé gíjà tó jẹ́ gbòógì ní ìlú yìí. Ilé-ìwé ìkọ́ṣẹ́ Asiwaju Bola Tinubu Skills Acquisition Centre, tí ìjọba àpapọ̀ Nàìjíríà kọ́ wà ní "'Ilẹ̀-Olúji". Gboluji Grammar School, Ile-Oluji jẹ́ ọkàn lára ọgọ́rùn-ún ilé-ìwé girama tó ti pẹ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Àwọn ilé-ìwé girama mìíràn ní ìlú yìí ni Holy Saviour's High School, Orere Grammar School, Baptist High School, CAC Grammar School, St. Francis College, Gloryfield International College, New Era High School àti Akinyosoye Model College. Àwọn ènìyàn tó lààmìlaaka ní Ile Oluji. Àwọn ènìyàn wọ̀nyí jẹ́ àwọn ènìyàn tó lààmìlaaka, tí wọ́n bi, tí ó gbé, tí ó sì ń gbé ní Ile-Oluji lọ́wọ́lọ́wọ́.
Ile Oluji
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17293
17293
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìlàòrùn Ilesa Ìlà Oòrùn Iléṣà jẹ́ agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní Naijiria. Olú ilé ìjọba ìbílẹ̀ náà wà ní Iyemogun ni ìlú Ilésà. Agbègbè náà tóbi tó 71 km², tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ 106,586 nígbà ìkànìyàn ọdún 2006. Kóòdù ìfìwéránṣé agbègbè yí sì jẹ́ 233.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìlàòrùn Ilesa
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17294
17294
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìwọòrùn Ilesa Agbegbe Ijoba Ibile Iwoorun Ilesa je ijoba ibile ni Ipinle Osun ni Naijiria. Ibujoko re wa ni Ereja.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìwọòrùn Ilesa
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17295
17295
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Illela Agbegbe Ijoba Ibile Ariwa Illela je ijoba ibile ni Ipinle Sokoto ni Naijiria. Ibujoko re wa ni Illela
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Illela
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17296
17296
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìlàòrùn Ilorin Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìlàòrùn Ilorin wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìlàòrùn Ilorin
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17297
17297
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Ilorin Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Ilorin wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Ilorin
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17298
17298
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìwọòrùn Ilorin Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìwọòrùn Ilorin wa ni Naijiria
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìwọòrùn Ilorin
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17299
17299
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Imeko-Afon Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìmẹ̀kọ-Àfọ̀n jẹ́ ìjọba-ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Imeko-Afon