url
stringlengths
37
41
id
stringlengths
1
5
text
stringlengths
2
134k
title
stringlengths
1
120
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18507
18507
Abédi Pelé
Abédi Pelé
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18510
18510
Abedi Ayew
Abedi Ayew
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18511
18511
Jesse Jackson Jesse Louis Jackson, Sr. (ojoibi October 8, 1941) je alakitiyan eto arailu omo orile-ede Amerika.
Jesse Jackson
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18512
18512
Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè (GIO) ni ona iwon gbogbo okowo orile-ede kan. Eyi ni iye owo itaja gbogbo oja ati isisefun to waye ninu bode orile-ede kan larin odun kan.
Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18513
18513
GDP
GDP
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18514
18514
Gross domestic product
Gross domestic product
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18515
18515
Agbegbe Ijoba Ibile Ariwa Egbado
Agbegbe Ijoba Ibile Ariwa Egbado
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18516
18516
André-Marie Ampère André-Marie Ampère FRS (20 January 1775 – 10 June 1836) je onimosayensi omo orile-ede Fransi ti o je gbigba gege bi oluwari isetannagberingberin.
André-Marie Ampère
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18519
18519
Odò Bẹ́núé Odò Benue (Faransé: la Bénoué), tí a mọ̀ sí Odò Chadda tàbí Tchadda, jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú àwọn odò tí ó ń sùn sínú Odò Niger. Odò yìí gùn tó ìwọ̀n ẹgbèje (Àádọ́rinlẹ́gbẹ̀rin) ìsun jágere dáadáa lásìkò ẹ̀ẹ̀rùn. Fún ìdí èyí, ó jẹ́ ọ̀nà pàtàkì ní àgbègbè tí ó ti ń ṣàn. Ojú-ilẹ̀. Ó máa gbéra láti Adamawa Plateau ní apá Àríwá Cameroon, ní apá ìwọ̀-oòrùn tí yóò ti gba ìlú Garoua àti amù-ìsọlọ́jọ̀ Lagdo ṣàn lọ sí apá gúúsù Nàìjíríà tí àwọn òkè Mandara, yóò gba Jimeta, Makurdi kí ó tó wà pàdé Odò Niger ní Lọ́kọ́ja. Àwọn ìsun-omi ńláńlá ni Odò Faro àti Gongola àti Mayo ní Kebbi, èyí tí ó so Odò Logone (lára odò Chad) lásìkò omíyalé. Àwọn ìsun-omi yòókù ni Odò Taraba àti Odò Katsina Ala. Níbi tí odò tí ń pàdé, odò Benue jù tí Niger lọ pẹ̀lú ìwọ̀n. Ìdásílẹ̀ gbòógì kí ó ti di ọdún 1960 jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ó lé irínwó (3,400) ìwọ̀n cubic ní ìṣẹ́jú àáyá (120, 000 cu ft/s) fún odò Benue tí Niger sì jẹ́ (2,500) ní ìṣẹ́jú àáyá (88,000 cu ft/s). Ni gbogbo ọdún yẹn, ìsun omi dinku torí pé kò sí omi. Omíyalé wáyé ní odò Benue ní oṣù Òwàrà, 2012 tí ó fa àlékún púpọ̀ bá àwọn ejò olóró ní ẹ̀kùn Duguri,  ìjọba Ìbílẹ̀ Alkaleri, Ìpínlẹ̀ Bauchi. Ìròyìn kan ní 2013 sọ pé ó lé igba èèyàn ti oró ejò ti pá ní ẹ̀kùn yìí. Iléwòsàn ìjọba ní Kaltungo, Ìpínlẹ̀ Gombe ní Nàìjíríà ní ibùdó ìtọ́jú tó súnmọ́ jù. "Ẹni tí orí bá kó yọ tí ó dé Kaltungo fún ìtọ́jú yóò padà láàárin sílé ọjọ́ méjì. i
Odò Bẹ́núé
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18521
18521
Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Òndó <onlyinclude>Èyí ni Àtòjọ àwọn Gómìnà àti àwọn Olùmójútó ti Ìpínlẹ̀ Òndó. Ìpínlẹ̀ Òndó jẹ́ dídásílẹ̀ láti apá ti Ìpínlẹ̀ Ìwọ̀orùn ní 17 Mar 1976. </onlyinclude>
Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Òndó
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18522
18522
List of Governors of Ondo State
List of Governors of Ondo State
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18523
18523
D'banj Dapo Daniel Oyebanjo tí a bí ni ọjọ́ kẹsàn-án, oṣù kẹfà, ọdún 1980 ní Zaria, Ipinle Kaduna, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bíi D'banj jẹ́ akọrin àti oníṣòwò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni oludásílẹ̀ Mo' Hits Records, tí Don Jazzy jẹ́ aṣàgbéjáde orin ní ilé-iṣẹ́ náà. Ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ̀, díẹ̀ lára wọn ni; akorin ilè Africa tó dára jù lọ ní MTV Europe Music Awards 2007, akọrin toh dára jù lọ ní ọdún 2009 ní MTV Africa Music Awards 2009, òṣèré tó dára jù lọ ni àgbáyé ní 2011 BET Awards, àti akọrin ilẹ̀ Africa tó nh tà jù ní 2014 World Music Awards. Oyebanjo mú orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ tí ń ṣe D'banj láti ara orúkọ àkọ́kọ́ rẹ̀, Dapo àti orúkọ bàbá rẹ̀, Oyebanjo. Ó di gbajúgbajà látara orin "Oliver Twist" tó kọ ní ọdún 2012. Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀. D'banj, tí àwọn èèyàn mọ̀ sí Kokomaster tàbí Bangalee, ni a bí ni ọjọ́ kẹsàn-án, oṣù kẹfà, ọdún 1980 ní Zaria, apá Àríwá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Bàbá rẹ̀ jẹ́ ajagun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kan rí, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ oníṣòwò láti ìlú Shagamu, ní Ogun. D'banj ní àwọn àbúrò tó jẹ́ ìbeji, Taiwo àti Kehinde Oyebanjo. Ìbẹ̀rẹ̀ orin kíkọ. Femi Oyebanjo, tí ń ṣe ẹ̀gbọ́n D'banj ló sọ D'banj di ẹni tó nífẹ̀ẹ́ orin kíkọ. Femi kú nígbà tó pé ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún nínú ọkọ̀ òfurufú kan tó já . Ìfẹ́ tí D'banj ní sí orin kíkọ borí ìtakò tó dojuhkọ láti ọ̀dọ̀ àwọn òbí rẹ̀. Oh tiraka láti gba àṣẹ lọ́wọ́ àwọn òbí rẹ̀, ìtàn yìí wà nínú orin rẹ̀ kan "All Da Way." Lẹ́yìn ikú ẹ̀gbọ́n rẹ̀, ó mú dùrù ẹ̀gbọ́n rẹ́, ó sì máa ń lò ó láti fi kọrin ní ilé-ilwé rẹ̀. Ọ̀pọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ló máa ń wá tẹ́tí si. Ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ láti lọ kọ́ mechanical engineering ní Lagos State University, àmọ́ kò parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ nítorí ìdaṣẹ́sílẹ̀ àwọn olùkọ́. Ó lọ sí ìlú London láti lọ parí ẹ̀kọ́ rẹ̀. Ibẹ̀ ló ti pàdé Don Jazzy, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ aṣógbà ní ilé-iṣẹ́ náà. Don Jazzy ràn án lọ́wọ́ láti gbé orin àkọ́kọ́ rẹ̀ "Tolongo" jáde. Àwọn ìtọ́kasí. blah blah blah
D'banj
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18526
18526
D banj
D banj
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18527
18527
Dapo Daniel Oyebanjo
Dapo Daniel Oyebanjo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18528
18528
Ita David Ikpeme <ns>0</ns> <revision> <parentid>74480</parentid> <timestamp>2013-04-18T08:58:10Z</timestamp> <contributor> <username>KLBot2</username> </contributor> <minor /> <comment>Bot: Migrating 1 interwiki links, now provided by Wikidata on </comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> Ita David Ikpeme je omo orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Ondo tele.
Ita David Ikpeme
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18532
18532
Sunday Tuoyo Sunday Tuoyo je omo orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Ondo tele.
Sunday Tuoyo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18533
18533
Adekunle Ajasin Michael Adekunle Ajasin (28 November 1908 - 3 October 1997) je omo orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Ondo tele.
Adekunle Ajasin
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18534
18534
Bode George Olabode Ibiyinka George je agba oloselu omo bibi ipinle Eko ni apa iwo-oorun orile-ede Naijiria. A bii ni ojo kokanlelogun, osu kokanla odun 1945. O ti figba kan je Gomina ijoba ologun Ipinle Ondo ni odun 1988 si 1990. Titi di asiko yii, Bode George je omo egbe-oselu alatako People Democratic Party
Bode George
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18535
18535
Sunday Abiodun Olukoya Sunday Abiodun Olukoya je omo orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Ondo tele.
Sunday Abiodun Olukoya
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18536
18536
Anthony Onyearugbulem Anthony Ibe Onyearugbulem (1955–2002) je omo orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Ondo tele.
Anthony Onyearugbulem
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18537
18537
Moses Fasanya Moses Fasanya je omo orile-ede Naijiria ati Gomina awon Ipinle Ondo ati Abia tele.
Moses Fasanya
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18538
18538
Akin Omoboriowo Akinwole Michael Omoboriowo (12 January, 1932 – 10 April 2012) je omo orile-ede Naijiria ati Igbakeji Gomina Ipinle Ondo tele.
Akin Omoboriowo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18539
18539
Michael Bamidele Otiko Michael Bamidele Otiko je omo orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Ondo tele
Michael Bamidele Otiko
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18540
18540
Ekundayo B. Opaleye Ekundayo B. Opaleye (1946-2023) je omo orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Ondo tele.
Ekundayo B. Opaleye
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18541
18541
Bamidele Olumilua Bamidele Isola Olumilua (ojoibi 1940) je omo orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Ondo tele.
Bamidele Olumilua
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18542
18542
Mike Torey Lucky Mike Torey je omo ologun orile-ede Naijiria totifeyinti ati Gomina awon Ipinle Ondo ati Enugu tele.
Mike Torey
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18543
18543
KSA
KSA
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18544
18544
King Sunny Ade
King Sunny Ade
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18545
18545
Sunday Adeniyi
Sunday Adeniyi
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18546
18546
Philadelphia <ns>0</ns> <revision> <parentid>462394</parentid> <timestamp>2015-11-01T13:50:06Z</timestamp> <contributor> <username>Magioladitis</username> </contributor> <minor /> <comment>/* Itokasi */removed deleted template, removed: using (11720)</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> Philadelphia () ni ilu titobijulo ni ipinle Pennsylvania ati ilu kefa nibi ti awon eniyan posijulo ni orile-ede Amerika.
Philadelphia
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18548
18548
Whitney Houston Whitney Elizabeth Houston (August 9, 1963 – February 11, 2012) je akorin ati osere ara Amerika. Ti a pe ni “Ohùn naa”, o jẹ ọkan ninu awọn oṣere orin ti o ta julọ ni gbogbo igba, pẹlu tita awọn igbasilẹ ti o ju 200 million lọ kaakiri agbaye. Houston ti ni ipa lori ọpọlọpọ awọn akọrin ninu orin olokiki, ati pe a mọ fun agbara rẹ, awọn ohun orin ẹmi ati awọn ọgbọn imudara ohun.
Whitney Houston
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18549
18549
R&B
R&B
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18550
18550
Philadelphia, Pennsylvania
Philadelphia, Pennsylvania
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18551
18551
March 26
March 26
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18552
18552
Orin Soul Orin Soul ni iru orin to bere wa lati orile-ede Amerika to sedapo awon apilese gospel music ati rhythm and blues.
Orin Soul
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18553
18553
Soul music
Soul music
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18554
18554
Rhythm and blues
Rhythm and blues
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18555
18555
January 13
January 13
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18556
18556
Marvin Gaye Marvin Pentz Gay, Jr., to gbajumo pelu oruko ori-itage re Marvin Gaye, (April 2, 1939 – April 1, 1984) je akorin omo orile-ede Amerika.
Marvin Gaye
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18557
18557
Marvin Pentz Gay <ns>0</ns> <revision> <timestamp>2010-01-23T19:09:12Z</timestamp> <contributor> <username>Demmy</username> </contributor> <comment>Redirected page to Marvin Gaye</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format>
Marvin Pentz Gay
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18559
18559
Curtis Mayfield <ns>0</ns> <revision> <parentid>462401</parentid> <timestamp>2013-03-11T11:46:44Z</timestamp> <contributor> <username>Legobot</username> </contributor> <minor /> <comment> Migrating 1 interwiki links, now provided by on </comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> Curtis Lee Mayfield (June 3, 1942 – December 26, 1999) je omo orile-ede Amerika akorin ati atokun soul, rhythm and blues, ati funk, ohun lo se atokun ati akorin fun filmu "Super Fly". Nitori bi ise orin bayi o je gbigba gege bi asiwaju ninu orin Funk ati awon orin awon ara Afrika Amerika to je mo toloselu.
Curtis Mayfield
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18561
18561
African-American
African-American
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18565
18565
June 3
June 3
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18566
18566
April 2
April 2
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18567
18567
April 1
April 1
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18568
18568
Los Angeles, California
Los Angeles, California
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18570
18570
December 26
December 26
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18571
18571
James Baldwin (writer)
James Baldwin (writer)
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18572
18572
United Arab Emirates
United Arab Emirates
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18573
18573
Ṣíṣọ̀kan àwọn Ẹ́mírètì Árábù
Ṣíṣọ̀kan àwọn Ẹ́mírètì Árábù
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18574
18574
Àjọṣepọ̀ Ìjọbapọ̀ tabi Orílẹ̀-èdè ìjọba àpapọ̀ tabi orile-ede apapo ni iru ijoba ibiti awon opo orile-ede ti darapo sokan lati ni ijoba kan soso larin ara won.
Àjọṣepọ̀
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18575
18575
Federation
Federation
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18576
18576
Sharjah Sharjah (; Arabic: الشارقة "ash-Shāriqa") je ikan ninu awon Emireti Àwọn Emireti Sisokan Arabu.
Sharjah
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18577
18577
UAE
UAE
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18578
18578
Sharjah (emirate)
Sharjah (emirate)
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18579
18579
Ajman Ajmān (tabi Ujman; Lárúbáwá: ‎ ‘ajmān) je ikan ninu awon Emireti meje orile-ede Awon Emireti Sisokan Arabu.
Ajman
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18580
18580
Fujairah Fujairah (Lárúbáwá: ‎, al-fuǧayrah) je ikan ninu awon Emireti meje ti won parapo je orile-ede Awon Emireti Sisokan Arabu.
Fujairah
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18581
18581
Ras al Khaimah Ras al-Khaimah (Lárúbáwá: ‎, rās al-Khaymah, to tumo si "The Top of the Tent"), mimo tele bi Julfar, je ikan ninu awon Emireti meje orile-ede Awon Emireti Sisokan Arabu.
Ras al Khaimah
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18582
18582
Um Al Quwain Umm al-Quwain (Arabiki: أمّ القيوين, umm al-quwwayn, to tumo si "Iya awon alagbara meji") je ikan ninu awon Emireti orile-ede Awon Emireti Sisokan Arabu.
Um Al Quwain
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18583
18583
Alice Walker Alice Malsenior Walker (ojoibi February 9, 1944) je olukowe omo orile-ede Amerika.
Alice Walker
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18586
18586
John Edgar Wideman John Edgar Wideman (ojoibi June 14, 1941, ni Washington, DC) je olukowe omo orile-ede Amerika.
John Edgar Wideman
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18587
18587
William Faulkner William Faulkner (September 25, 1897 – July 6, 1962) je olukowe omo orile-ede Amerika to gba Ebun Nobel ninu Litireso.
William Faulkner
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18588
18588
Bertrand Russell Bertrand Arthur William Russell, 3rd Earl Russell, OM, FRS (18 May 1872 – 2 February 1970) je onimo oye omo orile-ede Britani Botilejepe o gbe gbogbo ile aye re ni Ilegeesi, Welsi ni won ti bi, ibe na ni o si ku si.
Bertrand Russell
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18589
18589
Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándì The United Kingdom of Great Britain and Ireland
Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándì
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18591
18591
Ludwig Wittgenstein Ludwig Josef Johann Wittgenstein (26 April 1889 – 29 April 1951) je omo Austria-Britani onimo oye ti ise re ni pataki da le lori ogbon, imo-oye mathematiki, imo-oye okan, ati imo-oye ede.
Ludwig Wittgenstein
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18592
18592
Managua Managua ni oluilu orile-ede Nicaragua. Itokasi. <ns>10</ns> <id>18274</id> <revision> <id>402481</id> <parentid>368856</parentid> <timestamp>2012-10-29T09:22:11Z</timestamp> <contributor> <ip>80.128.82.91</ip> </contributor> <comment>iw</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format>
Managua
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18607
18607
Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Cross River <onlyinclude>This is a list of administrators and governors of Cross River State, Nigeria, including leaders of South-Eastern State. South-Eastern State was formed on 1967-05-27 when Eastern Region was split into East-Central, Rivers and South-Eastern states. The state was renamed Cross River State in 1976. </onlyinclude>
Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Cross River
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18609
18609
Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ábíá <onlyinclude> Èyí ni àkójọpọ̀ àwọn alákòóso àti àwọn gómìnà Ìpínlẹ̀ Abia ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí a dá sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ (Ògún) ọdún (1991)láti ìgbà tí ó ti dá dúró kúrò lábẹ́ àkóso Ìpínlẹ̀ IMO. "* Military administrators appointed by the ruling dictators of their respective times." </onlyinclude>
Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ábíá
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18612
18612
List of Governors of Abia State
List of Governors of Abia State
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18615
18615
List of Governors of Cross River State
List of Governors of Cross River State
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18616
18616
Donald Duke Donald Duke (ojoibi 30 September 1961 ni Calabar) lo je Gomina Ipinle Cross River, Nigeria lati 29 May 1999 titi di 29 May 2007. Je okan ninu awon oludari Voice of Nigeria ni 1991.
Donald Duke
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18625
18625
Paramaribo Paramaribo (àlàjẹ́: Par′bo) ni olú-ìlú àti ìlú tí ó tobí jùlọ ní orílẹ̀-èdè Suriname. Eti bebe odo Suriname ni agbegbe Paramaribo yi wa. Eniyan ti o to oji-le-nigba o le eyokan ni eto ikaniyan orile-ede Suriname ni odun 2012 se akosile re wipe o ngbe ni agbegbe Paramaribo. Ni apa ariwa-ila-oorun gusu Amerika ni agbegbe Paramaribo ti wa ri.
Paramaribo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18633
18633
Ikedi Ohakim
Ikedi Ohakim
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18637
18637
Stipe Mesić
Stipe Mesić
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18640
18640
Ivo Josipović Ivo Josipović [] (ojoibi 28 August 1957 ni Zagreb, PR Croatia, FPR Yugoslavia) ni Aare ile Kroatia lowolowo lati February 2010.
Ivo Josipović
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18641
18641
Hutu Awon Hutu (IPA: "Hūtū") je eya eniyan ni Arin Afrika agaga ni Rwanda ati Burundi.
Hutu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18642
18642
Ìlú Quezon Quezon City (Filipino: "Lungsod Quezon"), ni o ti je oluilu tele ati ilu titobijulo ni orile-ede Philippines.
Ìlú Quezon
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18654
18654
Lars Lokke Rasmussen
Lars Lokke Rasmussen
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18655
18655
Margrethe II of Denmark
Margrethe II of Denmark
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18656
18656
Arin Amerika
Arin Amerika
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18657
18657
Week
Week
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18661
18661
Moon
Moon
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18663
18663
Sun
Sun
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18664
18664
Month
Month
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18665
18665
Mùhammédù 6k ilẹ̀ Mòrókò Mohammed VI (Lárúbáwá: ‎) ni Oba orile-ede Morocco lowolowo. Won bi ni 21 August 1963, o si gori ite ni July 1999.
Mùhammédù 6k ilẹ̀ Mòrókò
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18666
18666
Abbas El Fassi Abbas El Fassi (Lárúbáwá: ‎; ojoibi September 18, 1940) ni Alakoso Agba orile-ede Morocco lati September 19, 2007.
Abbas El Fassi
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18667
18667
Luisa Diogo Luísa Dias Diogo (ojoibi April 11, 1958) je Alakoso Agba orile-ede Mozambique lati February 2004 titi di January 2010. O dipo Pascoal Mocumbi, to ti je Alakoso Agba fun odun mesan. Ki o to di Alakoso Agba, o je Alakoso Iseto ati Isuna, ipo to dimu titi di February 2005.
Luisa Diogo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18668
18668
Aires Ali Aires Bonifácio Ali (ojoibi 6 December 1955) ni Alakoso Agba orile-ede [Mozambique]] lowolowo lati January 16, 2010. Tetetele o je Gomina Igberiko Inhambane (2000-2004) ati Alakoso Eto Eko (2005-2010).
Aires Ali
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18669
18669
Carlyle Glean Sir Carlyle Arnold Glean, GCMG je oloselu ati Gomina Agba orile-ede Grenada. O je Alakoso Eto Eko ni igba ijoba Nicholas Brathwaite lati 1990 titi di 1995. Won yan sipo Gomina Agba ni November 2008.
Carlyle Glean
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18672
18672
Jean-Marie Doré Jean-Marie Doré (ojoibi 1939?) je oloselu ara orile-ede Guinea. O je Aare egbe oloselu Union for the Progress of Guinea (UPG) ati Alakoso Agba ile Guinea lati January 2010.
Jean-Marie Doré
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18673
18673
Sékouba Konaté Sékouba Konaté (ojoibi 1964) je oga ologun ni Ise Ologun ile Guinea ati Adipo Aare ile Guinea ti ijoba ologun ibe, National Council for Democracy and Development. Ohun ni Igbakeji Aare tele si Moussa Camara. Ni Oṣu Kẹwa ọdun 2021, o ti fẹyìntì lati ọmọ ogun.
Sékouba Konaté
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18674
18674
Moussa Dadis Camara
Moussa Dadis Camara
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18675
18675
Lansana Conté Lansana Conté ("c". 1934 – 22 December 2008) je Aare orile-ede Guinea lati 3 April 1984 titi di ojo iku re. Elesin musulumi lo je ati eya eniyan Susu.
Lansana Conté
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18676
18676
Muslim
Muslim
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18677
18677
Albert Camille Vital Albert Camille Vital (ojoibi on 18 July 1952) je oga ologun ara orile-ede Madagascar ati Alakoso Agba ijoba ibe lati 20 December 2009 nigba to ropo Eugène Mangalaza.
Albert Camille Vital
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18678
18678
Mohamed Abdul Quasim al-Zwai
Mohamed Abdul Quasim al-Zwai
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18679
18679
Miftah Muhammed K'eba Miftah Muhammed K'eba (Arabiki:مفتاح محمد كعيبة ) je oloselu ara orile-ede Libya.
Miftah Muhammed K'eba
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18698
18698
Ilé ọba àwọn Nẹ́dálándì Ilẹ̀ ọba àwọn Nẹ́dálándì (Dutch: ) jẹ́ orílè-èdè pẹ̀lú agbèègbè ní apá ìwoòrùn Europe (Netherlands) àti ní Karibeani (ẹ̀yún Aruba àti Netherlands Antilles).
Ilé ọba àwọn Nẹ́dálándì
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18699
18699
The Netherlands Antilles
The Netherlands Antilles
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=18700
18700
Flag of Anguilla
Flag of Anguilla